Ìgbéyàwó: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Ìlà 19:
'''Ìjọhẹn:''' Èyí ni ìgbésẹ̀ tí ẹbí ọkọ ìyàwó-ojúọ̀nà máa ń gbé láti ríi pé àwọn ẹbí ìyàwó-ojúọ̀nà gba láti fi ọmọbìnrin wọn fọ́kọ tí ó wá tọrọ rẹ̀. Ó dàbí ètò mọ̀mínmọ̀ọ́.
 
'''Ìdána:''' Lẹ́yìn Ìjọ́hẹn, ìdána ni ètò tó kàn nínú ayẹyẹ àṣà ìgbéyàwó láyé àtijó. Ìdána ni sísan àwọn ẹrù àti owó-orí tí ẹbí ìyàwó-ojúọ̀nà bá kà fún ọkọ-ojú ọ̀nà láti san.<ref name="Pulse Nigeria 2014">{{cite web | title=How It's Done In Yoruba Land | website=Pulse Nigeria | date=2014-10-02 | url=https://www.pulse.ng/traditional-marriage-rites-how-its-done-in-yoruba-land/6jk1dc0 | access-date=2019-11-14}}</ref>
 
'''Ẹkún-Ìyàwó:''' Èyí ni ayẹyẹ ìkẹyìn tí ìdílé ìyàwó máa ń ṣe fún omidan tí ó ṣetàn láti ṣe ìgbéyàwó kí ó tó forí lé ilé ọkọ rẹ. Omidan tí ó fẹ́ lọ ilé ọkọ ni ó máa ń sun ẹkùn ìyàwó. Omidan yìí a máa sún ẹkùn yìí láti dárò bí ó ṣe fẹ́ fi ilé bàbá rẹ̀ sílẹ̀ lọ sí ilé ọkọ. Ẹkún ayọ̀ ni èyí ẹkún ìyàwó máa ń jẹ́.
 
'''Ìgbéyàwó Gangan:''' Èyí ni ayẹyẹ tó kẹ́yìn láṣà ìgbéyàwó nílẹ̀ Yorùbá láyé àtijó. Ó máa ń wáyé lẹ́yìn tí àwọn ọkọ-ojúọnà bá ti san gbogbo ẹrù ìdána. Àwọn ìdílé ìyàwó-ojú ọnà yóò wa sètò láti sìn ìyàwó lọ ilé ọkọ rẹ. Ọ̀kan-ọ̀-jọ̀kan àwọn ẹbí ìyàwó àti ọkọ á máa wúre fún ìyàwó àti ọkọ rẹ̀ lọ́jọ́ ìgbéyàwó. Jíjẹ àti mímu máa ń pọ̀ lọ́pọ̀ yanturu.
 
==Pàtàkì Ìbálé Nínú Àṣà Ìgbéyàwó Láyé Àtijọ́==