Ifá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 1:
{{odù ifá}}
[[AWON ÒRÌSÀ TI YORUBA NSÌN]]
Ninu asa [[Yoruba]] '''Ifá''' A ti rí i ni ojú ewé 46 Apa Kini ìwe yi irú ipò pataki ti Orìsà-nla tabi Obàtálá kó laarin awon òrìsà ati irúnmalè ile Yoruba. A ti gbó pelu pe jákè-jádò gbogbo ilè Yorùbá ni nwon maa mbó ó, nitoripe oun ni awon àgbà àtijó gbà ninu ìtàn ìsèdálè won pe o je igbákejì Olódùmarè, ti o si nràn an lówó lati tún enia dá nipa fífún un ni ojú, imú, eti, ati gbogbo èyà ara miran ti o ye ki èdá ní ki o fi lè di enia pipe. ...
 
J.F. Odunjo (1969), Eko Ijinle Yoruba Alawiye, Fun Awon Ile Eko Giga, Apa Keji, Longmans of Nigeria, Ojú-ìwé 78-87.
(1) Òrìsà-nlá tabi Obàtálá
 
(2) Ifá tabi Òrúnmìlà
 
(3) Èsù tabi Elegbára
 
(1) Òrìsà Nlá tabi Obátálá
A ti rí i ni ojú ewé 46 Apa Kini ìwe yi irú ipò pataki ti Orìsà-nla tabi Obàtálá kó laarin awon òrìsà ati irúnmalè ile Yoruba. A ti gbó pelu pe jákè-jádò gbogbo ilè Yorùbá ni nwon maa mbó ó, nitoripe oun ni awon àgbà àtijó gbà ninu ìtàn ìsèdálè won pe o je igbákejì Olódùmarè, ti o si nràn an lówó lati tún enia dá nipa fífún un ni ojú, imú, eti, ati gbogbo èyà ara miran ti o ye ki èdá ní ki o fi lè di enia pipe. ...
 
J.F. Odunjo (1969), Eko Ijinle Yoruba Alawiye, Fun Awon Ile Eko Giga, Apa Keji, Longmans of Nigeria, Ojú-ìwé 78-87.
 
{{odù ifá}}
{{ekunrere}}
[[Category:Yoruba]]
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ifá"