Ẹ̀sìn Islam: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k corr using AWB
Fixed typo
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe lórí ẹ̀rọ alágbéká Android app edit
Ìlà 1:
[[Àwòrán:FirstSurahKoran.jpg|right|thumb]]
'''Ẹ̀sìn Ìmàle''' tabi '''Ẹ̀sìn Islàm''' ({{lang-ar|'''الإسلام'''}} ''{{transl|ar|al-’islām}},'' {{IPA-ar|ʔislæːm|pron|ar-al_islam.ogg}}<ref group=note>There are ten pronunciations of ''Islam'' in English, differing in whether the first or second syllable has the stress, whether the ''s'' is {{IPA-en|z|}} or {{IPA|/s/}}, and whether the ''a'' is pronounced {{IPA|/ɑː/}} as in ''father,'' {{IPA|/æ/}} as in ''cat,'' or (when the stress is on the ''i'') {{IPA|/ə/}} as in the ''a'' of ''sofa'' (Merriam Webster). The most common are {{IPA-en|ˈɪzləm, ˈɪsləm, ɪzˈlɑːm, ɪsˈlɑːm|}} (Oxford English Dictionary, Random House) and {{IPA-en|ˈɪzlɑːm, ˈɪslɑːm|}} (American Heritage Dictionary).</ref>)<ref>Alaiye nipa Esin Islam yi wa lati Alantakun Esin Islam ni ede Yoruba ti awon omo leyin [[:en:Sheikh Adelabu|Sheikh Dr. Abu-Abdullah Adelabu]] da sile nipase ijo Sheikh naa ti ise [[:en:AWQAF Africa|Awqaf Africa]] ni Ilu London > at [http://www.esinislam.com/MediaYoruba/index.php EsinIslam.Com]</ref> jẹ́ èsìnẹ̀sìn àlááfíà,ìrọ̀rùn àti ìjupá-jusẹ̀ sílẹ̀ fún Ọlọ́run aṣẹ̀dá gbogbo ayé nípa ṣ́iṣe ìfẹ́ àti títèlé àṣẹ rẹ̀ yálà o tẹ́ ọ lọ́rùn tàbí kò tẹ́ ọ lọ́rùn. Ó tún jẹ́ ẹ̀sin tí Ọlọ́run tún fi ránṣẹ́ sí gbogbo ayé látọwọ́ àwọn òjíṣ̣́e rẹ̀ tó ti rán wá ṣáájú ànọ́bì [[Muhammad]] ọmọ Abdullah (kí ìkẹ́ àti ọlà Ọlọ́hun ó ma bá a). Òun sì ni èsìnẹ̀sìn òtítọ tí èsìnẹ̀sìn mìíràn kò lè jẹ́ ìtẹ́wọ́gb̀a ní ọ̀dọ̀ Ọlọ́hun ([[Allah]]) yàtò sí òun nìkan. Ọlọ́hun (Allah) sì ti ṣe é ní èsìnẹ̀sìn ìrọ̀rùn tí kò sí ìṣòro kankan tàbí wàhálà níbẹ̀. Kò si ohun tí ó kọjá agbára wọn, bẹ́èbẹ́ẹ̀ sì ni kò sí ìjẹni nípá fún àwọn tí wọ́n gba èsìn náà. Bẹ́è tún ni ẹ̀siìnẹ̀sìn náà kò la ohun tí ó kọjá agbára wọn bọ̀ wọ́n lọ́rùn. Ìsìlámù ni ẹ̀sìn tí ó ṣe pé ìmọ̀-Ọlọ́hun ni (al- Taoheed) ní ìpìl̀ẹ rè, òdodo ni òpó rẹ̀, ó dá lórí deededéédé,otito. Òhun sì ni ẹ̀sìn tí ó gbópọn tí ó jẹ́ pé ó ń darí gbogbo ẹ̀dá sí ibi gbogbo ohun tí yó̀o jẹ́ ànfààní fún wọn ní ọ̀run àtayéàti ayé wọn. Bẹ́ẹ̀ náà ni ó sì tún ń kì wọ́n nílọ̀ nípa gbogbo ohun tí yó̀o ṣaburú fún wọn yálà láyé ni tàbí ọ̀run. Ohun ni esinẹ̀sìn ti OlohunỌlọhun (Allah) fi se atunse awon adi-okan ati awon iwa. Ohun naa ni O fi se atunse isemi aye ati ti orun. Oun ni OlohunỌlọhun (Allah) fi se irepoìrẹ́pọ̀ laarin awon okanọkàn ti o keyin si ara won ati awon ojukokoroojúkòkòrò ti o fonka. Nipase eyi ni O fi yoyọ awonàwọn ohun ti a ka si iwaju yii ninu okunkunòkùnkùn biribiri iro, ti O si se ifinimona rerẹ̀ lo si ibi otito, ti O si to si onaọ̀nà lolọ si ibi onaọ̀nà ti o ye kooro<ref>EsinIslam.Com ni oju-ewe pupo ti o so nipa eye. Fun ekunrere alaiye se abewo si Alantakun Yoruba naa nipa Islam [http://www.esinislam.com/Islamiyyat_Index/Muslim_Briefcase_Index.htm]</ref>.
 
* Esin Islam je oruko ise aiyelujara gbajugbaja ti [[:en:Sheikh Adelabu|Sheikh Dr. Abdul-Fattah Adelabu]] eni ti i se olori ati oludasile [[:en:AWQAF Africa|Awqaf Africa]] Asiwaju Esin fun awon alawo dudu ni ile [[:en:England|Geesi]] da sile lati ipase [http://www.esinislam.com/ EsinIslam.com] fun eko nipa Esin Islam pelu [[:en:AWQAF Africa Muslim Open College|Awqaf Africa Muslim Open College]] ni ilu [[London|London]].