Níji Àkànní: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Ìlà 10:
 
Gẹ́gẹ́bi ọ̀kan lára àwọn aṣojú mẹ́ta lati orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nibi ipatẹ Àṣà Olympiad ni ilu London ní ọdun 2012, òun ni olùdarí fún ''[[:en:The_Lion_and_the_Jewel|The Lion and the Jewel]]'', ere oniṣe ti Ọ̀jọ̀gbọ́n [[:en:Wole_Soyinka|Wole Soyinka]] kọ èyi ́tí a sọ di eré orí ìtàgé fún ìgbà àkọ́kọ́ ní ọdún 1959.<ref>{{cite web|url=http://www.punchng.com/feature/midweek-revue/200m-entertainment-fund-not-a-grant-boi/|title=$200m entertainment fund not a grant — BoI|work=The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper}}</ref> Ní ọdún 2005, oun ni igbákejì olùdarí fún sáà àkọ́kọ́ eto kan ti a pe ni [[:en:Amstel_Malta_Box_Office|Amstel Malta Box Office]], tii ṣe eto ori mohunmaworan ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó n fi igbe aye àwọn ènìyàn hàn.
 
Ní ọdún 2006, oun ni olùdarí ète fún eto kan ti a pe ni [[Big Brother Nigeria]], tíí ṣe ètò ori mohunmaworan tó n fi igbe aye àwọn ènìyàn hàn gbangba, ni ọdun yii bakanna, o fi ọwọ́sowọpọ pelu olùdarí miran lati dari fíìmú ti a mò sí ''The Narrow Path (Ọna tooro)'', tii ṣe fíìmú oní ìṣẹ́jú márùn-dín-lọ́gọ̀rún ti a ti ọwọ́ ilé iṣẹ́ Òpòmúléró (Mainframe Films and Television Productions) gbe jade, Tunde Kelani lo dari fíìmú naa. Fíìmú yii, ti òṣèré bíi Ṣọla Asedeko ati Khabirat Kafidipe kó'pa ninu rẹ ni ìtàn inu rẹ dá lórí ìwé ti a n pe àkọlé rẹ ni ''The Virgin'', (Wundia) tii ṣe iwe akoko ti a ti owo Bayo Adebowale kọ. Ní ọdún 2008, ó tún dari ''Abọ́bakú'', tii se fíìmú o ni kúkúrú ti Femi Odugbemi gbe jade lori ètò mohunmaworan MNET kan ti wọn pe ni iṣẹ kanṣe New Directions. ''Abọ́bakú'' gba àmì ẹ̀yẹ fun fíìmú kúkúrú ti o dara julo ni ajodun fíìmú ti ZUMA ni ilu Abuja, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni ọdún 2010, oun kanna ni a tún fún ni àmì ẹ̀yẹ fun fíìmú kúkúrú ti o dara julo ni ami eye TERRACOTA Awards ni ilu Eko, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
 
<br />