Níji Àkànní: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe lórí ẹ̀rọ alágbéká Android app edit
Ìlà 15:
 
Ní ọdún 2010, Akanni kọ eré Aramotu o si tun dari rẹ, Aramotu jẹ ere oniṣe lati orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,Gabriel Afolayan lo ko'pa ninu fíìmú náà. A darukọ fíìmú yii fun ami ẹ̀yẹ meje nibi Ayẹyẹ fíìmù ilẹ̀ adúláwọ̀ ẹlẹ́ẹ̀keje ó sì gba àmì ẹ̀yẹ fíìmù orílè-èdè Nàìjíríà tí ó dára jù lọ àti àmì ẹ̀yẹ fún fíìmù tí aṣọ wíwọ̀ rẹ̀ dára jù lọ. Fíìmù yìí kan náà ni ó gba àmì ẹ̀yẹ fún fíìmù tí ó dára jù lọ ní Àjọ̀dún Fíìmù lagbaye fún Ilẹ̀ Aláwọ̀ Dúdú tí ó wáyé ní ìlú Calabar ní oṣù karùn-ún ọdún 2013. A ti ṣe àfihàn Aramotu ni onírúurú àjọ̀dún fíìmù káàkiri àgbáyé, lára èyí tí àjọ̀dún Samsung Women's International Film Festival (SWIFF) ni ọdún 2012 ní ìlú Chennai, orílẹ̀-èdè India jẹ́; ní ọdún 2012 yìí kan náà àjọ̀dún fíìmù Africa In The Picture (AITP), ní ìlú Amsterdam ṣe àfihàn Aramotu; ní ọdún 2013, àjọ̀dún fíìmù Arusha African International Film Festival (AIFF), ní orílè-èdè Tanzania; àti àjọ̀dún International Film Festival of Kerala (IFFK), ní orílè-èdè India náà ṣe àfihàn fíìmù yìí.
 
He scripted and directed ''Heroes and Zeros'', a Nigerian drama film that stars Nadia Buari, Bimbo Manuel, Gabriel Afolayan, Linda Ejiofor and Olu Jacobs. The film was released on September 7, 2012 and premiered in the UK on March 15, 2013 at Odeon Cinema. The film won the Most Outstanding Film and Audience Choice awards at the 2013 EKO International Film Festival and competed in the digital film category of the 2013 Pan African Film and Television Festival, FESPACO, in Ouagadougou, Burkina Faso. It was invited to the 2013 International Film Festival of Kerala, IFFK, in India, and was also screened at the 2014 Afrikamera Film Festival in Warsaw, Poland. It received 6 nominations at the 9th Africa Movie Academy Awards and won the awards for Best Editing, Best Screenplay and Best Director