Pete Edochie: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
Ìlà 3:
Ìgbà èwe rẹ̀
 
Gẹ́gẹ́ bí a ṣe sọ ṣáájú, wọ́n bí Pete Edochie ní Ọjọ́ keje oṣù kẹta ọdún 1947. Ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Anambra ni ṣùgbọ́n Zaria, ní ìpínlẹ̀ Kaduna ló ti ṣe kékeré rẹ̀ dàgbà. Ó bẹ̀rẹ̀ ilé ìwé ní St. Patrick and James Primary School, Zaria, kí ó tó tẹ̀ síwájú ní St. John's College fún Ẹ̀kọ́ gírámà rẹ̀, lẹ́yìn èyí ló sí orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì fún ìtẹ̀síwájú ẹ̀kọ́ rẹ̀ tí ó sìn kàwé gboyè nínú ìmọ̀ oníwèé ìwé-ìròyìn àti ìgbóhùnsáfẹ̀fẹ̀. Lẹ́yìn èyí, ó ṣíṣe ní ilé iṣẹ́ ìjọba tó ń rí sí ọkọ̀ ojú-irin kí ó tó dára pọ̀ mọ́ ilé iṣẹ́ Nigeria Television Authority, NTA lọ́dún 1967 nígbà tó wà lọ́mọ ogún ọdún. Kò pẹ́ nídìí iṣẹ́ púpọ̀