Abiodun Olujimi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Created by translating the page "Abiodun Olujimi"
form, typos
Ìlà 1:
{{Infobox officeholder|name=Abiodun Christine Olujimi|image=|width=|office1=[[Nigerian Senate|Nigerian Senator]] for [[Ekiti State|Ekiti]] South|state1=[[Ekiti]]|term_start1=2015|term_end1=Till Date|predecessor1=|successor1=|birth_date={{birth date and age|1958|12|25|df=y}}|birth_place=|death_date=|party=[[People's Democratic Party (Nigeria)|Peoples' Democratic Party]] (PDP)|alma_mater=[[University of Abuja]], 2011<br/>Nigerian Institute of Journalism, 1976, 1994}}
'''Ab́iọ́dún Christine Olújìmí''' jẹ́ olósèlú Nàíjírìa, a bi ní ọjọ́ kẹẹ̀dọ́gbọ̀n oṣù kejìlá, ọdún 1958. <ref name="ITT">{{Cite news|last1=IT & Telecom|first1=Digest|title=Senator Abiodun Olujimi Is Diligent|url=http://www.ittelecomdigest.com/senator-abiodun-olujimi-is-diligent/|accessdate=8 March 2018}}</ref> Ó jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ asòfin orílẹ̀ Ẹ̀dẹ̀ Nàìjíríà, tí ó sojú fún agbègbè Gúúsù Ẹ̀kìtì àti olórí ìpín kékeré ọmọ ilé ìgbìmọ̀ asòfin ní Nàìjíríà. . Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ ti àjọ ìbáraenisọ̀rọ̀ ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
 
== Ìgbèsì ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ ==
A bí ní Òmùò Ẹ̀kìtì ní ìpínlẹ̀ Ẹ̀kìtì, Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ ní Ilé ìwé Àpóstélì ti obìnrin ní ìlú Ìbádán, Ìpínlẹ̀ Ọ̀yó, Ó tún tẹ̀síwájú lọ sí Ilé ẹ̀kọ́ Oníròyìn ti Nàìjíríà láti gba dípọ̀n ni ọdún 1976. Bíọ́dún Olújìmí tún kàwé jáde gboyè dìgirì ní ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì Òsèlú àti oyè dìgírì gíga ní ètò ìbátan àti ọjà títà ní Ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Àbújà. <ref name="EkD">{{Cite news|last1=Defenders|first1=Ekiti|title=Read Full Biography And Life History Of Abiodun Olujimi|url=http://ekitidefender.com/read-full-biography-life-history-abiodun-olujimi/|accessdate=9 March 2018|issue=7 February 2018}}</ref>
 
== Isẹ́ ==
Isẹ́ Bíọ́dún gégé bí agbóhùn sáfẹ́fẹ́ àti ońiróyìn gbèé, bótilẹ̀ jẹ́ pé kìí ṣe isẹ́ tí ó wùú láti ṣe. <ref name="Punch">{{Cite news|url=http://punchng.com/i-wanted-to-be-a-doctor-but-somehow-couldnt-senator-olujimi/|title=I wanted to be a doctor but somehow couldn’t – Senator Olujimi|last1=Baiyewu|first1=Leke}}</ref> Gẹ́gẹ́ bíi oníròyìn, ó ṣiṣẹ́ ní ilé ìwé ìròyìn Tribune, Ilé iṣẹ́ ̀ibáraenisọ̀rọ̀ àti if̀ìwéráńṣẹ́ ti Nà̀ijíríà, Ilé iṣẹ́ Telifísàn ti Nàìjíríà Ilé iṣẹ́ irin ní ìpínlẹ̀ Delta, Ovwian Aladja, Rífílẹ́sì, Tẹlifísàn DBN <ref name="EkD">{{Cite news|last1=Defenders|first1=Ekiti|title=Read Full Biography And Life History Of Abiodun Olujimi|url=http://ekitidefender.com/read-full-biography-life-history-abiodun-olujimi/|accessdate=9 March 2018|issue=7 February 2018}}</ref> àti alákóso ti Tẹlifísàn DBN lati 1993-1997 .
 
Ó darapọ̀ mọ́ ọkọ rẹ̀ nínú òsèlù <ref name="Punch">{{Cite news|url=http://punchng.com/i-wanted-to-be-a-doctor-but-somehow-couldnt-senator-olujimi/|title=I wanted to be a doctor but somehow couldn’t – Senator Olujimi|last1=Baiyewu|first1=Leke}}</ref> ní ọdún 1997 gẹ́gẹ́ bií akọ̀wé àgbáyé ti ìjoba àpapọ̀ ti NCPN, Ó kọjá lọ sínú ẹgbẹ́ APC , ẹgbẹ́ onígbálẹ̀ lẹ́yìn tí ẹgbẹ́ titẹ́lẹ̀ parun, ó tún jẹ akọ̀wé àpapò fún egbẹ́ APC. <ref name="EkD">{{Cite news|last1=Defenders|first1=Ekiti|title=Read Full Biography And Life History Of Abiodun Olujimi|url=http://ekitidefender.com/read-full-biography-life-history-abiodun-olujimi/|accessdate=9 March 2018|issue=7 February 2018}}</ref>
 
Ní ọdún 2002, ó darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ aláburadà (PDP) leyíi tí ó bẹ̀rẹ̀ àseyorí rẹ̀ nínú òsèlú. Ọdún 2003 ni wọ́n yàn àn gẹ́gẹ́ bií Olùrànlọ́wọ́ sí Gòmìnà ìpínlẹ̀ Ẹ̀kìtì, láti ibẹ̀ wọ́n dìbò yan gẹ́gẹ́ bí omo ilé ìgbìmọ̀ asòfin àpapò. Ó di igbákejì Gómìnà pèlú Gómìnà Ayò Fáyose ní ọdún 2005. Olùjìmí dé ipò giga nínú òsèlú, láti ipò `komísáńná tí ó wà fún iṣẹ́ àti ohun amú ayé derùn àti ọ̀gá àgbà olùdárí. O díje fún ipò sénétò ti o n sojú fún ẹkùn gúúsu Èkì̀tì ní ilé ìgbìmọ̀ asòfin lábé asìá ẹ̀gbẹẹ alábùradà. <ref name="EkD">{{Cite news|last1=Defenders|first1=Ekiti|title=Read Full Biography And Life History Of Abiodun Olujimi|url=http://ekitidefender.com/read-full-biography-life-history-abiodun-olujimi/|accessdate=9 March 2018|issue=7 February 2018}}</ref>
 
Abíọdún Olújìmì jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn olósèlú tí ó ní ìrírí jùlo ní orílè èdè Nàíjíríá .
 
Ẹgbẹ́ alábùradì (PDP) ẹ̀ka ti Ẹ̀kìtì yà án sí ipò adarí ẹgbẹ́, ní ọdún 2018 láti jẹ́ kí ẹgbẹ́ náà gbaradì fún ìdìbò ọdùn 2019. Ojomoyele, Rotimi . “ A dúró tí Olújìmí gẹ́gẹ́ bíi adarí wà ní Ìlú Ẹ̀kìtì fùn egbé a~lábúràdà (PDP) Iwe Ìròyìn Fàngàdì ti Nàìjíríà, Nàìjíríà. Gba ní ỌjỌ́ kokànlá,osù keta, Ọdún2019.
 
Nínú ìdìbò gbogbo gbòò ti ọdún 2019, ó fi ìdí rẹmi gẹ́gẹ́ bíi asojú fún gúúsù Ẹ̀kìtì fún ẹgbẹ́ APC. Síbẹ̀síbẹ̀, Ilé ẹjọ́ kotẹ́milọ́rùn polongo rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi ẹni tí ó jáwé olúborí asojú gúúsù Ẹ̀kìtì ní ilé ìgbìmọ̀ asòfin. Nítorínáà, Adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin búra fún un ní ọjọ́ kẹrìnlá, osù kọkànlá ọdún 2019.
 
== Àwọn ìtọ́kasí ==
{{Reflist}}
 
[[Ẹ̀ka:Àwọn ènìyàn alààyè]]
[[Ẹ̀ka:Àwọn ọjọ́ìbí ní 1958]]