Ìsọdipúpọ̀: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
Ìlà 2:
[[Fáìlì:Multiplication Sign.svg|thumb|right|Àmì ìsọdipúpọ̀.]]
'''Ìsọdipúpọ̀''' jẹ́ iṣẹ́ nínú mathematiki tó ń ṣe ìgbéga nọ́ḿbà kan pẹ̀lú òmíràn. Ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọ̀nà [[ìṣirò alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀|ìṣirò]] mẹ́rin tó wa (àwon yioku ni [[ìròpọ̀]], [[ìyọkúrò]], àti [[pínpín]]).
<ref name="Boyer 2016">{{cite web | last=Boyer | first=Carl B. | title=A history of mathematics : Carl B. Boyer : Free Download, Borrow, and Streaming : Internet Archive | website=Internet Archive | date=2016-10-23 | url=https://archive.org/details/historyofmathema00boye | access-date=2019-12-15}}</ref>
 
Fún àwon [[nọ́mbà adaba]] ìsọdipúpọ̀ jẹ́ ìlọ́po tó ń yípo. Fún àpẹrẹ ìsọdipúpọ̀ 3 pẹ̀lú 4 (tàbí 3 lọ́nà 4) ṣẹ é ṣírò nípa ríro 3 mẹ́rin pọ̀ mọ́ ara wọn: