Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Èdè Bàlóṣì"

No change in size ,  12:05, 26 Oṣù Kejìlá 2019
Fixed typo
(Fixed typo)
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
 
|lc4=bcc|ld4=Southern Balochi|notice=Indic}}
 
Ọmọ ẹgbẹ́ èdè tí a ń pé ní Iranian ni Bàlúṣì. Àwọn tí ó ń sọ ọ́ tọ́ mílíọ̀nù márùn-ún. Púpọ̀ nínú àwọn tí ó ń sọ ọ́ yìí ni ó wà ní Pakísítáánì (Pakistan) ní Bàlúṣísítáànì (Baluchistan). Baluclistan yìí ni ìpínlẹ̀ (province) tí ó wà ní apá ìwọ̀-oòrùn jùní pakcstan. Àwọn tí ó ń sọ èdè yìí ní Baluchistan tó múlíọ̀nùmílíọ̀nù (Iran), Afuganíísítáànù (Afghanistan) àti In-índíà (India). Àkọtọ́ Lárúbáwá (Arabic) ni wọ́n fi kọ ọ́ sílẹ̀. Àjọ kan wà tí wọ́n ń pè ní Baluchi Academy tí ó ń ń sí pé àkọsílẹ̀ èdè yìí páye.
<ref name="Omniglot 2019">{{cite web | title=Baluchi language, alphabet and pronunciation | website=Omniglot | date=2019-06-16 | url=https://www.omniglot.com/writing/baluchi.php | access-date=2019-11-20}}</ref> <ref name="Institutionen för lingvistik och filologi 2019">{{cite web | title=The Balochi Language Project - Uppsala universitet | website=Institutionen för lingvistik och filologi | date=2019-11-15 | url=https://www.lingfil.uu.se/forskning/the-balochi-language-project/ | access-date=2019-11-20}}</ref>