Ryutaro Hashimoto: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Fixed typo
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Added content
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Ìlà 58:
|term_end8 = 11 September 2005
}}
'''Ryutaro Hashimoto''' (橋本 龍太郎 ''Hashimoto Ryūtarō'', tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 1937<ref>{{cite news|url=https://www.theguardian.com/news/2006/jul/03/guardianobituaries.japan|title=Obituary: Ryutaro Hashimoto|last=Reed|first=Christopher|date=2 July 2006|newspaper=[[The Guardian]]|access-date=7 January 2017}}</ref> tí ó sì kú ní ọjọ́ kìíní oṣù keje ọdún 2006) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè [[Japan]] tó di [[Prime Minister of Japan| Alákòóso Àgbà ilẹ̀ Japan]] láti ọjọ́ kọkànlá oṣù kìíní ọdún 1996 títí di ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù keje ọdún 1998. Ó jẹ́ adarí ọ̀kan lára àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú tí ó lágbára jù lọ ní orílẹ̀-èdè náà kí ó tó di pé ó kọ ìṣèlú sílẹ̀. Nítorí ìtìjú, kò kópa nínú ìdìbò gbogboogbò tí orílẹ̀-èdè Japan ní ọdún 2005. Ó kú ní ọjọ́ kìíní oṣù keje ọdún 2006 ní ilé-ìwòsàn kan ní ìlú Tokyo.<ref name="The Economist 2006">{{cite web | title=Ryutaro Hashimoto | website=The Economist | date=2006-07-11 | url=https://www.economist.com/obituary/2006/07/11/ryutaro-hashimoto | access-date=2019-12-28}}</ref>
 
 
{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}
 
==Àwọn Ìtọ́kasí==