Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "John Stith Pemberton"

Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
 
 
'''John Stith Pemberton''' tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹjọ oṣù keje ọdún 1831 (July 8, 1831) tí ó sìn kú ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹjọ 1888 (August 16, 1888) jẹ́ onímọ̀ ìjìnlẹ̀ sáyẹ́nsì [[biochemist]] àti oluṣẹ̀dá ohun mímu ẹlẹ́rìndọ̀dọ̀, [[Coke|Cola-cola]] ọmọ orílẹ̀ èdè [[Amẹ́ríkà]]. Ó tún jẹ́ ajagunfẹ̀yìntì tí ó jagun abẹ́lé tí orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Lọ́dún 1886 ló ṣẹ̀dá [[Coke|Coca-Cola]] tí ó sìn ta ẹ̀tọ́ ìṣẹ̀dá rẹ̀ fún ilé iṣẹ́ Coca-Cola Company kí ó tó kú. <ref name="Lemelson-MIT Program">{{cite web | title=John S. Pemberton | website=Lemelson-MIT Program | url=https://lemelson.mit.edu/resources/john-s-pemberton | access-date=2020-01-03}}</ref> <ref name="Griffenhagen Stieb Fisher 1999 p. 23">{{cite book | last=Griffenhagen | first=G.B. | last2=Stieb | first2=E.W. | last3=Fisher | first3=B.D. | title=A Guide to Pharmacy Museums and Historical Collections in the United States and Canada | publisher=American Institute of the History of Pharmacy | series=New Series | year=1999 | isbn=978-0-931292-34-7 | url=https://books.google.com/books?id=O1KpXC4dDSkC&pg=PA23 | access-date=2020-01-03 | page=23}}</ref> <ref name="NPGallery Search">{{cite web | title=NPGallery Asset Detail | website=NPGallery Search | url=https://npgallery.nps.gov/AssetDetail/NRIS/71000283 | access-date=2020-01-03}}</ref>
 
==Àwọn Ìtọ́kasí==
{{Reflist}}
2,809

edits