Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Ìyá"

205 bytes added ,  11:56, 10 Oṣù Kínní 2020
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
[[Fáìlì:iya.jpg|thumb|right|Ìyá àti [[ọmọ]] rẹ̀]]
'''Ìyá''' ('''màmá''' tabi '''mọ̀nmọ́n''') ni [[òbí]] tó jẹ́ [[obìnrin]] èèyàn kan. Ìyá àti [[bàbá]] jẹ́ òbí fún ọmọ tàbí ènìyàn kan. Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ìgbà, ìyá ló máa ń bí ọmọ fún ara rẹ̀, nígbà mìíràn ó lè [[ìgbàlọ́mọ|gba]] ọmọ ẹlòmíràn bí ọmọ rẹ̀ tàbí kí ó gba ọmọ ẹlòmíràn tọ́.<ref name="Google">{{cite web | title=MOTHER - meaning in the Cambridge English Dictionary | website=Google | url=https://dictionary.cambridge.org/dictionary/english/mother | access-date=2020-01-10}}</ref>
 
==Itokasi ==
2,904

edits