Akátá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Taxobox
 
Ìlà 1:
{{Taxobox
{{about|Ẹranko abìjà||Cheetah (disambiguation)}}
{{pp-semi-protected|small=yes}}
{{good article}}
{{EngvarB|date=December 2019}}
{{Speciesbox
| name = Cheetah
| fossil_range = [[Pleistocene]]–[[Holocene]], {{fossilrange|1.9|0}}
| status = VU
| status_system = IUCN3.1
| status_ref =
| status_ref =<ref name=iucn>{{cite iucn |last1=Durant |first1=S. |last2=Mitchell |first2=N. |last3=Ipavec |first3=A. |last4=Groom |first4=R. |title=''Acinonyx jubatus'' |year=2015 |volume=2015 |page=e.T219A50649567 |doi=10.2305/IUCN.UK.2015-4.RLTS.T219A50649567.en }}</ref>
| image = Cheetah (Acinonyx jubatus) female 2.jpg
| image_caption = Female cheetah in [[KwaZulu Natal]], South Africa
Line 21 ⟶ 17:
* [[Northeast African cheetah]] (''A. j. soemmeringii'') <small>([[Leopold Fitzinger|Fitzinger]], 1855)</small>
* [[Northwest African cheetah]] (''A. j. hecki'') <small>([[:de:Max Hilzheimer|Hilzheimer]], 1913)</small>
| synonyms_ref =<ref name = mammal/>
| synonyms = {{collapsible list
|''Acinonyx guepard'' <small>[[:de:Max Hilzheimer|Hilzheimer]], 1913</small>
Line 57 ⟶ 53:
}}
 
'''Akátá''' (''Acinonyx jubatus''; {{IPAc-en|ˈ|tʃ|iː|t|ə}}) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹbí ológbò tó tóbi jùlọ tí wọ́n sì pọ̀ lórílẹ̀ alààyè. [[Felidae|ológbò]] Ẹ̀yà ẹranko yí wópọ̀ jùlọ ní agbègbè Sàhárà [[North Africa|Àríwá ilẹ̀ Adúláwọ̀]],[[Southern Africa|Southern]], [[East Africa]], àti àwọn díẹ̀ lára ìletò ní orílẹ̀ -èdè [[Iran]]. Ẹranko yí fẹ́ràn láti máa gbé ní àwọn orílẹ̀ gbígba, níbí tí koríko pẹ́ṣẹ́pẹ́ṣẹ́ wà. <ref name="Smithsonian's National Zoo 2016">{{cite web | title=Cheetah | website=Smithsonian's National Zoo | date=2016-04-25 | url=https://nationalzoo.si.edu/animals/cheetah | access-date=2020-01-11}}</ref>
 
==Ìrísí rẹ̀==
Akátá jẹ́ ẹranko tí ó ní àwọ̀ àmúlù-málà oríṣiríṣi bí awọ̀ Yẹ́lò, funfun, tí awọọ̀ dúdú ara rẹ̀ sì tó ẹgbẹ́ẹ̀rún méjì níye. Ẹranko yí kìí fi bẹ̀ẹ́ sanra, orí rẹ̀ kò tàbí ó sì rí roboto. Awọ̀ irun dúdú ni ó pààlà tí ó sì yí ojú rẹ̀ po. Àyà ẹranko yí fẹ̀ ó sì jìn sínú díẹ̀ ní ìwọ̀n {{convert|70|-|90|cm|in|abbr=on}} . Ó ga nílẹ̀, ẹsẹ̀ rẹ̀ sì tíínrín, Bákan náà ni ó ní ìrù aláwọ̀ kànákìní tí ó gùn níwọ̀n ẹsẹ̀ bàtà. Èyí tí ó bá tàbí jùlọ lò ma ń gbésìọ̀n tó {{convert|21|-|72|kg|abbr=on}}<ref name="Kruger Park Wildlife">{{cite web | title=Facts About Cheetahs | website=Kruger Park Wildlife | url=http://www.krugerpark.co.za/Kruger_National_Park_Wildlife-travel/kruger-park-wildlife-cheetahs.html | access-date=2020-01-11}}</ref>
 
<ref name="Kruger Park Wildlife">{{cite web | title=Facts About Cheetahs | website=Kruger Park Wildlife | url=http://www.krugerpark.co.za/Kruger_National_Park_Wildlife-travel/kruger-park-wildlife-cheetahs.html | access-date=2020-01-11}}</ref>
==Bí wọ́n ṣe ń ṣọdẹ==
Gẹ́gẹ́ bí a ti mọ̀ wípé ẹranko yí ni ó yára , tí ó mọ eré sá ju ohunkóhun lọ ní orí ilẹ̀. Ó lè sá iye kìlómítà Mẹ́rìnlélọ́gọ́ta láàrín wákàtí kan, àyà fún ìdinwọ̀n ọ̀nà jíjìn {{convert|64|km/h|mph|abbr=on}} lásìkò tí ó bá fẹ́ pẹran jẹ,ó sì lè sa ìwọ̀n {{convert|112|km/h|mph|abbr=on}} fún ọ̀nà tí kò jìn {{convert|100|m|ft|abbr=on}}. Látàrí ìjáfáfá rẹ̀ yí ni kò fi sí ẹranko tó ṣòro fun láti kọlù láì pa.<ref name="Cheetah Conservation Fund 2019">{{cite web | title=About Cheetahs • Cheetah Facts • Cheetah Conservation Fund • | website=Cheetah Conservation Fund | date=2019-03-01 | url=https://cheetah.org/learn/about-cheetahs/ | access-date=2020-01-11}}</ref>
{{convert|112|km/h|mph|abbr=on}}
fún ọ̀nà tí kò jìn {{convert|100|m|ft|abbr=on}}. Látàrí ìjáfáfá rẹ̀ yí ni kò fi sí ẹranko tó ṣòro fun láti kọlù láì pa.<ref name="Cheetah Conservation Fund 2019">{{cite web | title=About Cheetahs • Cheetah Facts • Cheetah Conservation Fund • | website=Cheetah Conservation Fund | date=2019-03-01 | url=https://cheetah.org/learn/about-cheetahs/ | access-date=2020-01-11}}</ref>
 
==Àwọn Ìtọ́kasí==
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Akátá"