Àwọn Ogun Napoleon: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 78:
Ìjàgbara tí a n pe ní revolution tí ó selè ní [[France]] jé kí Fance ní òtá púpò ní ìlú Òyìnbó. Èyí ni ó sì fa ogun tí ó selè láàrin 1792 sí 1815 tí ó férè máa dáwó dúró.
Ní àsìkò ogun yìí, ilè [[Faransé]] ní Ògágun kan tí orúko rè n jé [[Nepoleon Bonaparte]]. Òpòlopò ogun ni Napoleon sé. Léyìn ìgbà tí ó ti ségun wònyí, ó so ara rè di emperor ní 1804. Léyìn ìgbà tí ó ti di olórí ilè Faransé tán ó tún fé di olórí gbogbo ìlú Òyìnbó. Nítorí ìdí èyí, gbogbo ìlú Òyìnbó ni ó wá gbógun tì í kí àbá rè yìí má baà lè se.
Àwon ìlú tó n bá ilè Faransé jà nígbà náà ni Austria, Prussia, Russia, Britain àti Spain. Àwon omo ogun ilè Faransé pò gan-an ni. Wón sé òpòlopò ogun. Àwón eléyìí tí ó se pàtàkì jù ni ogun Marengo àti Hohenlinden ní 1800 ti Austerlitz ní 1805 àti ti Jena ní 1806. Ìségun yìí fún Napoleon ní agbara láti máa darí ilè ìlú Òyìnbó.