Ẹ̀sìn Islam: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
→‎Esin Islam Ni Soki: Mo ṣe àtúnṣe àmì ọ̀rọ̀
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe lórí ẹ̀rọ alágbéká Android app edit
alphabetize at top of own category; capitalize section heading; remove stub template
Ìlà 109:
Ni akotan , a le e fowogbaya re pe ISLAM ti kakoja mimo asepo ti o yanran-un-tan ati ise ti o ye kooro laarin eru Olohun (eda) ati Adeda re ni abala kan, ati laarin omo eda eniyan ati awujo ti o n gbe nibe ninu gbogbo alaamori re ni abala miran. Ko si rere kan ninu awon iwa ati awon ibalo ayafi ki o je pe o ti se ifinimona awon atele re sibe ti o si se won lojukokoro nipa diduro tii gboin -gboin. Bee si ni ko aburu kan ninu awon iwa ati awon ibalo ayafi ki o je pe o ti ki won nilo gidigidi nipa atimasunmo o ti o si ko o fun won. Eyi ni o fi wa n han wa gedegbe pe esin ti ko labujeku kankan ni ISLAM je, esin ti o si dara ni pelu ti a ba gbe yiri wo ni gbogbo ona<ref>Esin Islam ni ede Yoruba ti [[:en:Sheikh Adelabu|Sheikh Dr. Abu-Abdullah Adelabu]] da sile ni Ilu London > at [http://www.esinislam.com/MediaYoruba/index.php EsinIslam.Com]</ref>.
 
{{ekunrere}}
== Ikiyesi ==
{{Reflist|group=note}}
 
== itokasiItokasi ==
{{reflist}}
 
== Ijapo lori Internet ==
* [http://www.esinislam.com/ EsinIslam.com]
 
{{Àyọkà dáradára}}
 
[[Ẹ̀ka:Ìmàle| ]]