Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Ọbẹ̀"

2 bytes removed ,  09:41, 20 Oṣù Kínní 2020
==Oríṣi ọbẹ̀ tó wà==
Ó yẹ kí a pààlà rẹ̀ wípé oríṣiríṣi ọbẹ̀ lò wà ní oríṣiríṣi ìlú tàbí ilẹ̀ àgbáyé, kódà ní ilẹ̀ [[Africa|Adúláwọ̀]] pàá pàá jùlọ ní ilẹ̀ [[Yorùbá]]. Ọbẹ̀ sísè dá lórí bí ìlú tàbí àwọn ènìyàn ibẹ̀ bá ṣe gbáfẹ́ nípa ónjẹ sí ni. Díẹ̀ lara àwọn ọbẹ̀ ilẹ̀ [[Yorùbá]] ni :
*'''[[Omi ọbẹ̀]]''',
*[['''[[Ọbẹ̀ ata'':]]'''
*[['''[[Ọbẹ̀ ẹ̀fọ́]]''']]
*[['''[[Ọbẹ̀ ẹ̀gúsí]]''']]
*'''[[Ọbẹ̀ yíyọ̀]]'''àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
*[['''Ọbẹ̀ yíyọ̀''']] àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. <ref name="BBC Good Food 2013">{{cite web | title=Soup | website=BBC Good Food | date=2013-05-28 | url=https://www.bbcgoodfood.com/recipes/collection/soup | access-date=2020-01-20}}</ref><ref>{{cite web |url=http://www.journalgazette.net/apps/pbcs.dll/article?AID=/20081109/FEAT0103/811090311 |title=Soup vs. stew: Difference in details |last=Goltz |first=Eileen |publisher=The Journal Gazette (Fort Wayne, Indiana) |date=9 November 2008 |accessdate=6 March 2010 |url-status=dead |archiveurl=https://web.archive.org/web/20110811025536/http://www.journalgazette.net/apps/pbcs.dll/article?AID=%2F20081109%2FFEAT0103%2F811090311 |archivedate=11 August 2011 |df=dmy-all }}</ref>
 
==Àwọn Ìtọ́kasí==