Ata ilẹ̀: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Ṣ'èdá ojúewé pẹ̀lú " '''Ata ilẹ̀''' (''Zingiber officinale'') jẹ́ ohun ọ̀gbìn tí ó ń tinú ilẹ̀ ju tàbí jáde. Wọ́n ma ń lòó lọ́pọ̀ ìgbà fún ohun èlò..."
 
Ẹ̀ka; template for scientific name
Ìlà 1:
'''Ata ilẹ̀''' (''{{lang-la|Zingiber officinale''}}) jẹ́ ohun ọ̀gbìn tí ó ń tinú ilẹ̀ ju tàbí jáde. Wọ́n ma ń lòó lọ́pọ̀ ìgbà fún ohun èlò ìsebẹ̀, tàbí oògùn tàbí àgbo.<ref name="nccih">{{cite web|url=http://nccih.nih.gov/health/ginger/|title=Ginger, NCCIH Herbs at a Glance|date=1 Sep 2016|publisher=US [[National Center for Complementary and Integrative Health|NCCIH]]|accessdate=2 Feb 2019}}</ref> Ó tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ohun ọ̀gbìn tí kìí tètè kú tí ó sì ma ń pẹ́ kí ó tó bàjẹ́. Ọdọdún ni ata ilẹ̀ ma ń ju lójú ibi tí wọ́n bá gbìín sí tí wọ́n sì ti kórè rẹ̀.
 
'''Ata ilẹ̀''' (''Zingiber officinale'') jẹ́ ohun ọ̀gbìn tí ó ń tinú ilẹ̀ ju tàbí jáde. Wọ́n ma ń lòó lọ́pọ̀ ìgbà fún ohun èlò ìsebẹ̀, tàbí oògùn tàbí àgbo.<ref name="nccih">{{cite web|url=http://nccih.nih.gov/health/ginger/|title=Ginger, NCCIH Herbs at a Glance|date=1 Sep 2016|publisher=US [[National Center for Complementary and Integrative Health|NCCIH]]|accessdate=2 Feb 2019}}</ref> Ó tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ohun ọ̀gbìn tí kìí tètè kú tí ó sì ma ń pẹ́ kí ó tó bàjẹ́. Ọdọdún ni ata ilẹ̀ ma ń ju lójú ibi tí wọ́n bá gbìín sí tí wọ́n sì ti kórè rẹ̀.
==Ìrísí rẹ̀==
Nígbà tí ata ilẹ̀ bá ń ju, ó ma ń ga tó ìwọ̀n Mi ta kan tí ó sì ma ń ní èwe sọ́ọ́rọ́ tí ewé náà m ń rí bí ìdá olójú méjì. Àwọn èwe rẹ̀ ma ń dì pọ̀ láti ilẹ̀ ni tí wọn yóò sì ya ẹ̀ka tí wọ́n bá dókè tán. Ẹ̀wẹ̀, awọ olómi aró yẹ́lò àti pọ́pù ni èwe rẹ̀ ma ń ní.<ref>{{Cite book|title=Plant resources of South-East Asia: no.13: Spices|vauthors=Sutarno H, Hadad EA, Brink M|publisher=Backhuys Publishers|year=1999|isbn=|veditors=De Guzman CC, Siemonsma JS|location=Leiden (Netherlands)|pages=238–244|chapter=Zingiber officinale Roscoe}}</ref>
Ìlà 6:
==Awọn Ìtọ́kasí==
{{Reflist}}
 
[[Ẹ̀ka:Àwọn ọ̀gbìn]]