Èdè Yorùbá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 14:
|iso1=yo|iso2=yor|iso3=yor}}
'''Èdè Yorùbá''' Ni èdè tí ó ṣàkójọ pọ̀ gbogbo káàrọ̀ o-ò-jíire, níapá ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ [[Nàìjíríà]], tí a bá wo èdè Yorùbá, àwọn onímọ̀ pín èdè náà sábẹ́ ẹ̀yà Kwa nínú ẹbí èdè Niger-Congo. Wọ́n tún fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé ẹ̀yà Kwa yìí ló wọ́pọ̀ jùlọ ní sísọ, ní ìwọ̀ oòrùn aláwọ̀ dúdú fún ẹgbẹẹgbẹ̀rún ọdún. Àwọn onímọ̀ èdè kan tilẹ̀ ti fi ìdí ọ̀rọ̀ múlẹ̀ pé láti orírun kan náà ni àwọn èdè bí Yorùbá, Kru, Banle, Twi, Ga, Ewe, Fon, Edo, Nupe, Igbo, Idoma, Efik àti Ijaw ti bẹ̀rẹ̀ sí yapa gẹ́gẹ́ bi èdè ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tó dúró láti bí ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ọ̀dún sẹ́yìn.
<ref name="SOAS University of London 2011">{{cite web | title=Yorùbá: Languages of Africa at SOAS University of London | website=SOAS University of London | date=2011-02-21 | url=https://www.soas.ac.uk/africa/languages/languages-of-africa-at-soas-yorb.html | access-date=2020-02-01}}</ref>
 
Ọ̀kan pàtàkì lára àwọn èdè orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ni èdè Yorùbá. Àwọn ìpínlẹ̀ tí a ti lè rí àwọn olùsọ èdè [[Yorùbá]] nílẹ̀ [[Nàìjíríà]] ni [[Edo state|ìpínlẹ̀ Ẹdó]], [[Ondo State|ìpínlẹ̀ Òndó]], [[Osun State|ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun]], [[Ọyo State|ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́]], [[Lagos State|ìpínlẹ̀ Èkó]], àti [[Ogun State|ìpínlẹ̀ Ògùn]]. Ẹ̀wẹ̀ a tún rí àwọn orílẹ̀-èdè míràn bí [[Tógò]] apá kan ní Gúúsù ilẹ̀ [[America|Amẹ́ríkà]] bí i [[Cuba]], [[Brasil]], [[Haiti]], [[Ghana]], [[Sierra Leone]],[[United Kingdom]] àti [[Trinidad]], gbogbo orílẹ̀-èdè tí a dárúkọ wọ̀nyí, yàtọ̀ sí orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]], òwò ẹrú ni ó gbé àwọn ẹ̀yà Yorùbá dé ibẹ.