Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Eṣinṣin ilé"

24 bytes added ,  13:15, 28 Oṣù Kejì 2020
Ẹ̀ka
k (Deborahjay ṣeyípòdà ojúewé Eṣinsin iléEṣinṣin ilé: Yoruba spelling with diacritic letters)
(Ẹ̀ka)
==Ìbálòpọ̀ ìyẹ́yin àti ìpamọ rẹ̀==
Eṣinṣin ilé tí ó jẹ́ abo ma ń sábà ní àṣepọ̀ ní ẹ̀ẹ̀kan, tí ó sì ma ń gbé [[àtọ̀]] akọ kiri láti lòó nígbà tí àsìkò àti yẹ́yin bá tó. Ó ma ń yé ẹyin tí ó tó ọgọ́rùn ún nípa sísàba lé ohun kan tí ó ti ń jẹrà bí ónjẹ bíbàjẹ́ tàbí ìgbẹ́. Àwọn ẹyin yí ni wọ́n ma ń yíra padà sí ohun abẹ̀mí tí kò lẹ́sẹ̀ tí a mọ̀ sí [[[ìdin]].<ref name="Encyclopedia Britannica">{{cite web | title=Housefly - insect | website=Encyclopedia Britannica | url=https://www.britannica.com/animal/housefly | access-date=2020-02-28}}</ref>
 
==Àwọn Ìtọ́kasí==
{{Reflist}}
 
[[Ẹ̀ka:Kòkòrò]]