Ifá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
No edit summary
Ìlà 1:
{{odù ifá}}
'''Ifá''' jé òrìsà kan pàtàkì láàrinláàárín àwonàwọn [[ọmọ Yorùbá|Yorùbá]]. ÀwonÀwọn Yorùbá gbàgbógbàgbọ́ wí pé Olódùmarè ló rán ifá wá láti òde òrunọ̀run latí wá fi ogbónọgbọ́n rẹ̀ tún ilé ayé seṣe. OgbónỌgbọ́n, ìmòìmọ̀, àti òye tí olódùmarè fi fún ifá ló fún ifá ní ipò ńlá láàrinláàárín àwonàwọn ìbọ ní ileilẹ̀ Yorùbá. “A-kéré-finú-sogbón”ṣọgbọ́n” ni oríkì ifá.
 
Ìgbàgbọ́ Yorùbá ni wípé ní ìgbà kan rí, ifá gbé ọ̀de-ayé fún ìgbà pípẹ́ kí o tóó padà lọ sí ọ̀rùn. Ní ìgbà tí ifá fi wà ní ilé ayé, ó gbé ilé-ifẹ̀ funfún ìgbà péréte. Ṣùgbọ́n ní ìgbà tí ọ̀rùnmìlà fi wà láyé yìí naanáà, a tún maamáa lọ sí òde ọ̀run lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan tí olódùmarè bá pèé láti wá fi ọgbọ́n rẹ̀ bá òun tún òde-ọ̀rùn ṣe. Nítorí náà gbáyégbọ́run ni ifá ńṣe.
 
Ìtàn sọ fún wa wipe ọmọ mẹ́jo ni ọ̀rúnmìlà bí nígbà tí ó wà láyé, nígbà tí ó di ọjọ kan ti ọ̀rùnmìlà ńṣe ọdún ni ọ̀kan nínú àwọn ọmọ yìí tíí ṣe àbíkèhìn pátápátá báse àfójúdi sí ọ̀rúnmìlà, ni ọ̀rùnmìlà bá binú fi ayé sílẹ̀ lọ sí òde ọrun. Ni ìfá bá relé olókun kòdé mọ́. Ó lẹ́ni tẹ́ bá ri i, ẹ ṣá maa pè ní baba”. Ṣùgbọ́n ọ̀rùnmìlà fún àwọn ọ̀mọ rẹ̀ méjẹ̀ẹ̀jọ náà ní ikin mẹ́rìndínlọ́gùn ó ní bẹ ẹ délé bẹẹ bá fówóó ní, ẹni tẹ̀ ẹ́ maa bi ninu.
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ifá"