Ifá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Ìlà 35:
Fun àpẹẹrẹ, tí ènìyàn bá fẹ́ se nǹkan. ti o ba bèrè lọ́wọ́ ifá, wọ́n le sọ pé ki o lọ rubọ fun ògun, Ẹbọ ifá jẹ́ ètùtù pàtàkì nítorí tí Babaláwo bání kí ènìyàn se nǹkan óní láti se é, ki òun pàápàá ólè ba à ni ìgboyà wípé àteégún-àteésà, nítori èyí ní àwọn babaláwo fi máa ńwí fún ẹní tí a ní kí ó rúbọ̣ pé kí ó wá oúnjẹ fún àwọn aládùgbóó rẹ.
 
== ÈṢÙÈṣù ATI IFÁàti Ifá==
 
Bí a ba wọ ilé àwọn babaláwo, a ó ri i wí pé ère [[Èsù]] kìí wọ́n nibẹ̀. Yangí ńlá kan o máa wà ní ẹ̀bá ilé àwọn babalawo. Yangí yìí dúró fún àmì Ẹ̀sù. Ìgbà gbogbo ni àwọn babaláwo máa gbé ẹbọọ lọ si ibẹ́, nwọn a máa bu epo lé yangí náà lórí, a máa rin sún nígbà gbogbo.
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ifá"