Ogun Àgbáyé Kìíní: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
Motún àwon òrò kan se
Ìlà 16:
|casualties2='''Military dead:'''
4,386,000
'''Military wounded:'''
8,388,000
'''Military missing:'''
3,629,000
'''Total:'''
16,403,000 KIA, WIA or MIA [[World War I casualties|...''further details''.]]

'''ÌJÀ OGUN ÀGBAYÉ KÌÍNÍ''' Láti ọjọ́ ti aláyé ti dáyé ni àwọn ìwọ̀ búburú bí i: jàgídígàganjàgídíjàgan, wàhálà. Irúkèrúdò ti wà nínú ìgbésí ayé ọmọ ènìyàn. Rògbòdìyàn kò yé sẹlẹ̀, bẹ́ẹ̀ nì làásìgbò kò roko ìgbàgbé. Ìdàrúdàpọ̀ nínú ẹbí, Àríyànjiyàn láàárin ọ̀rẹ́. Gbọ́nmisi, omi ò to kò yé wáyé láàárín ìlú sí ilu, abúléko sí abúléko. Gbogbo àwọn nǹkan ló ń parapọ̀ tí ó sì ń di ogun.

Tí a bá fi ojú sùnnǹkùnsùnùkùn woo gun àgbáyé kìíní, a óò rí wí pé gbogbo rògbòdìyàn, àjàkú akátá tó wáyé, kò sẹ̀yìn ìwà ìgbáragaìgbéraga, owú jíjẹ, èmi ni mo jùọ́ lọ, ìwọ lo jùmí lọ láàárín àwọn ọmọ adárúwurunadáríwurun. Àwọn àgbà sì bọ̀ wọ́n “àìfàgbà fẹ́nìkan ni kò jẹ́ káyé ó gún”. Nígbà tí ẹnìkan bá rò pé òun ló mọ nǹkan ṣe jú, èrò tòun ló tọ̀nà jù, kò sí ẹni tó gbọ́dọ̀ ta ko ohun tí òun bá sọ. Àwọn nǹkan wọ̀nyí tó máa ń bí ogun, nígbà tí elòmírà bá ta ko irúfẹ́ èèyàn bẹ́ẹ̀ tàbí kí ó jẹ gàba lé òun lórí. Bí ogun ṣe máa ń sẹlẹ̀ láàárin ìlú sí ìlú ló máa ń sẹlẹ̀ láàárín orílẹ̀-èdè sí orílẹ̀-èdè.

Ara àwọn nǹkan tí ó sokùn fa ogun àgbáyé àkọ́kọ́ nìyí Ogun àgbáyé àkọ́kọ́ yìí bẹ̀rẹ̀ láàárin orílẹ̀-èdè méjì kan tí orúkọ wọn ń jẹ́ Austria-Humgary ati Serbia. Ìlú kékeré kan ní awọn orílẹ̀-èdè méjèèjì yìí ń jà lé lórí. Orílẹ̀-èdè àkọ́kọ́ ló kọ́kọ́ gba ìlú yìí lọ́wọ́ ẹ̀kẹjì nínú ogun kan tó wáyé ní ọdún 1908. Orílẹ̀-èdè kejì wá ń dún kòkò lajà láti gba ìtú yìí padà. Sáájú àsìkò yìí, àwọn ìsẹ̀lẹ̀ kan sẹ̀lẹ̀ tí ó bẹ̀rẹ̀ sí mú kí àwọn orílẹ̀-èdè àgbáyé máa ṣe gbún-ùn gbùn-ùn gbún-ùn sí ara wọn. Sáájú ogun àgbéyé kìíní, àwọn orílẹ̀-èdè ló máa ń jẹ gàba lórí àwọ́n orílẹ̀-èdè mìíràn nígbà máà, kò pẹ́ kò jìnnà tí àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ní mú sìn yìí bẹ̀rẹ̀ ń jà fún òmìnira.