Orúkọ Àdúgbò ní Ìjẹ̀bú-Igbó, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
 
Ìlà 8:
 
3. Àdúgbò: Itúndosà.
Ìtumò: Àwon Yorùbá máa ń pe àdúgbò ní “itún nígbà míràn, àdúgbò ti won ń pè ni itún yìí wà ni Ìjèbú Igbo, se ni àwon ara àdúgbò dédé jí ni ojo kan, won rí i ti omitomi iti di odò nla sí apá kan itún won. Káwí káfò, àwon ara itún bèrè sì ni pa eja nínú odò náà. Báyìí ni wón so àdúgbò náà di “Itúndòsà”. Won a sì máa pe àwon ti won wá lati àdúgbò yìí ni “Omo Ìdósà maye”.
 
4. Àdúgbò: Igbáàìré – Igbáìre-
Ìlà 34:
 
10 Àdúgbò: Òkè Erefòn
Ìtumò: Ní ìgbà Ìwásè, Efòn ńlá kan wa ni Àdúgbò yìí ti o máa ń dààmú àwon ènìyàn ti won bá fe bojá lo sí oko. Odò nlá kan sì wà ni orí òkè ibì ti Efòn yìí máa ń lúgo sí. Bí àwon eniyàn ba ń darí bò lati oko won máa ń bu omi mu ninu odò yìí. Tí enikeni bá se ohun míràn yàtó sí mímu nínú omi náà, Efòn yóò fi imú onitòhún fon fèèrè. Sùgbón ti Efòn wáà bá ti rí wí pé won ń mu omi ni, kì yóò se ohunkóhun fun irú eni béè, won yóò sì la omu náà dúpé lówó Olódùmarè wí pé àwon gun òkè Efòn, ati wí pé omitomi iti àwon mu ninu odò ti re Efòn té lati má se ìjàmbá titi àwon fi gun òkè. Won wa so àdúgbò náà di òkè Odò re’fòn teti àgékúrú rè wá di “Òkè-erèfon”
 
11. Àdúgbò: Ládugbó
Ìtumò: Ládugbó ni èdè Ìjèbú túmò sí ìkokò ni Yorùbá àjùmòlò. Ìtàn sò wí pé Odò ńlá kan wà ni àdúgbò yìí ti ìkòkò (ládugbó) àbáláyé kan wà nínú rè. Tí àwon enìyàn bá fé pon omi múmu, nínú Ládugbó yìí ni won ti máa ń pon-ón. Sùgbon, bi o ba je ki a fo aso, ìwè ati ohun miran ni won a lo omitomi í ó yí Ládigbó náà kà á. Nígbà ti o se won se àdúgbò náà di “Odò-o-Ládugbó” ti àgékúrú rè wá di Lágugbó.
 
12. Àdúgbò: Igà Eran
Ìlà 74:
 
23. Àdúgbò: Iwáta
Ìtumò: Ní ìgbà ti àwon ènìyàn bá je Oyè tan ní ìlú, àwon Ìjòyè a sì wá sí Iwájú ìta àafin Oba pèlú àwon ebí, ara ati òré won-lati wa jó, lati se àjoyò pèlú Olóyè tuntun. Nígbà ti ó so àwon ènìyàn féràn lati máa se ayeye orísirìsì ni iwájú ìta àafin Oba nitori pé enikeni ti o ba fe se ayeye ti Oba bat i gbó nipa rè ni yóò ri èbùn gbà lówó Oba. Báyìí ni won, bèrè sì lo ìtà Oba fun ayeye, bí won ba sì fé se àpèjúwe ìbì ti won yóò ti se ayeye fun àwon ará, òré, ati ojúlùmò, won a ni kí wón wá bá won se ayeyreayeye ni iwájú ìta Oba. Níbo ni e o ti se ayeye? “iwáta Oba ni” kèrèkèrè wón so àdúgbò náà di “Iwátá”.
 
24. Àdúgbò: Òkè Ererú