Ìran Yorùbá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
Ìlà 23:
|related-c= [[Bini people|Bini]], [[Nupe]], [[Igala]], [[Itsekiri]], [[Ebira]]
}}
'''Àwọn ọmọ Yorùbá ''' ti a pè ni ẹ̀nìyàn Yorùbá ni ibí yìí pọ̀ gan-an ni. Ilẹ̀ Yorùbá ni púpò nínú wọ́n wa ni [[ìpínlẹ̀ Ẹdó]], [[Ìpínlẹ̀ Èkìtì]], [[Èkó]], [[Ìpínlẹ̀ Kwara]], [[Kogí]], [[ìpínlẹ̀ Ògùn]], [[Ìpínlẹ̀ Oǹdó]], [[Ọ̀ṣun]], [[ìpínlẹ̀ oyo|Ọ̀yọ́]]; àti wípé ọmọ Yorùbá wa ní orílẹ̀-èdè Olómìnira Benin ([[Dahomey]]), Sàró ([[Sierra Leone]]) àti [[Togo]], [[Brazil]], [[Cuba]], [[Haiti]], [[United States of America|Amẹ́ríkà]] ati Venezuela. Àwọn Yorùbá ni wọ́n se ipo keta ni pipo ni ile [[Naijiria]].
 
Awon Yoruba je awon eniyan kan ti ede won pin si orisirisi. Awon ipin yii ni a n ri; a maa lo ipin ede lati fi pe'ede wa ti n se bi ti "americas"; "ekiti"; "eko"; "ijebu"; "ijesha"; "ikale"; "oyo"; ati bebe lo. Laarin eyi, la sii tun ni ede ifo ti nse apere ede to nipin si awon ipin ede ti o po.