Ọ̀fun: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Ṣ'èdá ojúewé pẹ̀lú "{{Infobox anatomy | Name = Esophagus | Latin = Oesophagus | Image = Tractus intestinalis esophagus.svg | Caption = The digestive tract,..."
 
No edit summary
Ìlà 14:
| Lymph =
}}
'''Ọ̀fun''' ({{IPAc-en|ᵻ|ˈ|s|ɒ||f|ə|ɡ|ə|s}}), tí a tún mọ̀ sí '''ònfà óúnjẹ''' ni ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀yà ara inú tí ódà bí okùn oníhò tí ó ń ṣíṣẹ́ gbígbé óúnjẹ láti [[ẹnu]] lọ sí inú [[ikùn]] tí ó wà ní ara gbogbo ohun abẹ̀mi tí ó bá ti ń jẹ tàbí mu ohun kóhun. [[:wiktionary:fibromuscular|fibromuscular]]. Ọ̀fun yí dà bí ahòho tí ó gùn ní ìwọ̀n mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n lára àgbàlagba ènìyàn 25&nbsp; tí ó rọra gba ẹ̀yìn okùn ohùn, [[ọkàn]] àti iṣan atẹ́gùn tàbí èémí kọjá, tí ó sì fẹnu sọlẹ̀ sí inú ikùn. Lásìkò tí a bá ń gbé óúnjẹ mì lọ́wọ́, [[gògóńgò]] yóò dí pa lọ́wọ́ ẹ̀yín kí a má ba lè gbé óúnjẹ párí. <ref>{{cite web|url=https://abcnews.go.com/Health/thanksgiving-tales-emergency-room/story?id=43746804|title=Thanksgiving Tales From the Emergency Room|first=Julia|last=Jacobo|date=24 November 2016|website=ABC News}}</ref>
{{TOC limit|3}}
==Àwọn Ìtọ́ka sí==
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ọ̀fun"