Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Gògóńgò"

26 bytes removed ,  07:56, 5 Oṣù Kẹrin 2020
(Ṣ'èdá ojúewé pẹ̀lú "{{Infobox anatomy | Name = Throat | Latin = gula<br />jugulum | Image = Throat_Diagram.png | Caption = The human throat....")
 
 
==Iṣẹ́ rẹ̀==
Gògóńgò ni ó ń ṣàkóso bí ohun jíjẹ àti mímu kò ṣe ní gba òdì nípa ṣíṣètò ìyàtọ̀ láàrin ònfà [[ọ̀fun]], [[ohùn]] àti [[tááná]] tí ó gbé èémí jáde nígbà tí a bá ń jẹun lọ́wọ́. Gògóńgò tí a ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ yí náà ni ó tún gbé ọ̀pá ẹ̀jẹ̀ (blood vessel) oríṣríṣi. Gògóńgò ẹranko elégungun ní oríṣríṣi eegun méjì tí a mọ̀ sí (egungun hyoid) àti (clavicle).<ref>{{DorlandsDict|eight/000108480|throat}}</ref>
Ẹ̀wẹ̀, gògóńgò tún ń ṣíṣẹ́ pẹ̀lú [[ẹnu]], [[etí]],[[imú]] àti púpọ̀ nínú àwọn ẹ̀yà ara gbogbo.<ref>{{cite web|url=http://www.chop.edu/conditions-diseases/throat-anatomy-and-physiology#.VcTciyZViko|title=Throat anatomy and physiology|publisher=Children's Hospital of Philadelphia|accessdate=7 August 2015August15}}</ref> {{cn|date=August 2019}}
 
==Àwọn Ìtọ́kasí==
{{Reflist}}