Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "People's Democratic Party"

Lead sentence and infobox: correct name per official website; full section heading
(Lead sentence and infobox: correct name per official website; full section heading)
{{Infobox political party
|country = Nigeria
|party_name = People'sPeoples Democratic Party
|party_logo = [[Fáìlì:PDP-Flag-Logo.JPG|150px]]
|chairman = [[Uche Secondus]]
}}
 
'''Peoples Democratic Party [PDP]''' jẹ́ [[ẹgbẹ́ òṣèlú]] alátakò ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]]. Wọ́n dá ẹgbẹ́ òṣèlú yìí sílẹ̀ lọ́dún 1998. Àwọn ni ọmọ ẹgbẹ́ wọn ṣe ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà títí di ọdún 2015 kí ẹgbẹ́ òṣèlú [[All Progressives Congress]] tó gbàjọba àpapọ̀ lọ́wọ́ wọn. Ààrẹ orílẹ̀ èdè [[Nàìjíríà]] mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; [[Olúṣẹ̀gún Ọbásanjọ́]], [[Umaru Musa Yar'Adua]] àti [[Goodluck Jonathan]] ni ẹgbẹ́ yìí jẹ kí ẹgbẹ́ APC tó dà wọ́n lágbo nù lọ́dún 2015, tí Ààrẹ [[Muhammadu Buhari]] tí ẹgbẹ́ [[APC|APC]] fi wọlé gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ.
'''People's Democratic Party|[[PDP]]'''
 
jẹ́ [[ẹgbẹ́ òṣèlú]] alátakò ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]]. Wọ́n dá ẹgbẹ́ òṣèlú yìí sílẹ̀ lọ́dún 1998. Àwọn ni ọmọ ẹgbẹ́ wọn ṣe ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà títí di ọdún 2015 kí ẹgbẹ́ òṣèlú [[All Progressives Congress]] tó gbàjọba àpapọ̀ lọ́wọ́ wọn. Ààrẹ orílẹ̀ èdè [[Nàìjíríà]] mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; [[Olúṣẹ̀gún Ọbásanjọ́]], [[Umaru Musa Yar'Adua]] àti [[Goodluck Jonathan]] ni ẹgbẹ́ yìí jẹ kí ẹgbẹ́ APC tó dà wọ́n lágbo nù lọ́dún 2015, tí Ààrẹ [[Muhammadu Buhari]] tí ẹgbẹ́ [[APC|APC]] fi wọlé gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ.
 
{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}
 
== ItokasiÀwọn Ìtọ́kasí ==
{{reflist}}
 
{{Àwọn ẹgbẹ́ olóṣèlú Nàìjíríà}}
[[Ẹ̀ka:Àwọn ẹgbẹ́ olóṣèlú ní Nàìjíríà]]