People's Democratic Party: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
No edit summary
No edit summary
}}
 
'''Peoples Democratic Party [PDP]''' (''Ẹgbẹ́ Dẹmokrátíkì àwọn Aráàlú'') jẹ́ [[ẹgbẹ́ òṣèlú]] alátakò ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]]. Wọ́n dá ẹgbẹ́ òṣèlú yìí sílẹ̀ lọ́dún 1998. Àwọn ni ọmọ ẹgbẹ́ wọn ṣe ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà títí di ọdún 2015 kí ẹgbẹ́ òṣèlú [[All Progressives Congress]] tó gbàjọba àpapọ̀ lọ́wọ́ wọn. Ààrẹ orílẹ̀ èdè [[Nàìjíríà]] mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; [[Olúṣẹ̀gúnOlúṣégun Ọbásanjọ́]], [[Umaru Musa Yar'Adua]] àti [[Goodluck Jonathan]] ni ẹgbẹ́ yìí jẹ kí ẹgbẹ́ APC tó dà wọ́n lágbo nù lọ́dún 2015, tí Ààrẹ [[Muhammadu Buhari]] tí ẹgbẹ́ [[APC|APC]] fi wọlé gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ.