Muhammadu Buhari: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
#askme
Ìlà 45:
}}
 
'''Muhammadu Buhari''' (tí wọ́n ní Ọjọ́ ketàdínlógún, Oṣù Kejìlá Odún 1942) jẹ́ Aàrẹ orílẹ̀ èdè [[Nigeria|Nàíjíríà]] tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ dìbò yàn sípò láti odún 2015. Òun náà ló tún wọlé lẹ́ẹ̀kejì gẹ́gẹ́bí Ààrẹ nínú ìdìbò Ààrẹ tí wọ́n dì lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́dún 2019. <ref name="Abang 2019">{{cite web|last=Abang|first=Mercy|title=Nigeria's Muhammadu Buhari sworn in for second term as president|website=Google|date=2019-05-29|url=https://www.aljazeera.com/news/2019/05/nigeria-muhammadu-buhari-sworn-term-190529112615886.html|access-date=2019-09-24}}</ref> o
Buhari tí fìgbà kan jẹ́ ogágun Méjọ̀ Gẹ́nẹ́rà tí ó ti fèyìntì àti pé ó j̣e olórí orílẹ̀ èdè Nàíjíríà lati 31 Oṣù kejìlá odún 1983 sí Oṣù kẹjó odún 1985, léyìn tí ó fi ọ̀nà èbùrú kúùpù ológun gbàjọre.<ref name="Buhari-Idiagbon">{{cite web |url=http://www.dawodu.com/buhari.htm |title=Military Regime of Buhari and Idiagbon, January 1984 - August 1985 |accessdate=12 September 2013}}</ref><ref name="Siollun">{{cite news |url=http://www.dawodu.com/siollun3.htm |title=Buhari and Idiagbon: A Missed Opportunity for Nigeria |author=[[Max Siollun]] |publisher= Dawodu.com| date=October 2003 |accessdate=12 September 2013}}</ref>