Orílẹ̀ èdè America: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 2:
 
{{Infobox Country
| conventional_long_name = ÀwọnOrílẹ̀-èdè Ìpínlẹ̀Ìṣọ̀kan Aṣọ̀kanàwọn ilẹ̀Ìpínlẹ̀ Amẹ́ríkà
| native_name = ''United States of America''
| common_name = àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan ilẹ̀ Amẹ́ríkà
Ìlà 74:
| footnote4 = The population estimate includes people whose usual residence is in the fifty states and the District of Columbia, including noncitizens. It does not include either those living in the territories, amounting to more than four million U.S. citizens (most in [[Puerto Rico]]), or U.S. citizens living outside the United States.
}}
'''ÀwọnOrílẹ̀-èdè Ìpínlẹ̀Ìṣọ̀kan Aṣọ̀kanàwọn ilẹ̀Ìpínlẹ̀ Amẹ́ríkà''' ''(I.A.A)'' tabi '''ÀwọnOrílẹ̀-èdè Ìpínlẹ̀ AsokanAmẹ́ríkà''' (''I.AUSA'' tabi ni Geesi: ''USAUS'' tabi ''US''sọ́kí ní gẹ̀ẹ́sì), tàbí '''Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà''' tabi '''Amerika''' ni soki, jẹ́ orílé-èdè ijoba àpapò olominira pèlú [[iwe-ofin ibagbepo]] tí ó ni [[Awon Ipinle Amerika|adota ipinle]], [[agbegbe ijoba-apapo kan]] ati [[agbegbe merinla]], ti o wa ni [[Ariwa Amerika]]. Ilẹ̀ re fe lati [[Pacific Ocean|Òkun Pasifiki]] ni apa iwoorun de [[Òkun Atlántíkì]] ni apa ilaorun. O ni bode pelu ile [[Kanada]] ni apa ariwa ati pelu [[Meksiko]] ni apa guusu. Ipinle [[Alaska]] wa ni ariwaiwoorun, pelu Kanada ni ilaorun re ati [[Russia|Rosia]] ni iwoorun niwaju [[Bering Strait]]. Ipinle [[Hawaii]] je [[archipelago|agbajo erekusu]] ni arin Pasifiki. Orile-ede awon Ipinle Aparapo tun ni [[Territories of the United States|opolopo agbegbe]] ni [[Caribbean|Karibeani]] ati Pasifiki.
 
Pelu 3.79 egbegberun ilopomeji maili (9.83 million km<sup>2</sup>) ati iye to ju 309 egbegberun eniyan lo, awon Ipinle Aparapo je orile-ede totobijulo [[List of countries and outlying territories by total area|keta tabi kerin]] bii apapo iye aala, ati iketa totobijulo bii [[List of countries and outlying territories by land area|aala ile]] ati bi awon [[List of countries by population|olugbe]]. O je kan ninu awon orile-ede agbaye to ni [[Multiethnic society|opolopo eya eniyan]] ati [[multiculturalism|asapupo]], eyi je nitori ikoreokere lati opo awon orile-ede.<ref name="DD">Adams, J. Q., and Pearlie Strother-Adams (2001). ''Dealing with Diversity''. Chicago: Kendall/Hunt. ISBN 0-7872-8145-X.</ref> [[Economy of the United States|Okowo awon Ipinle Aparapo]] ni okowo orile-ede to tobijulo lagbaye, pelu idiye [[Gbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè|GIO]] 2009 to je $14.3 egbegberunketa (idamerin [[Àkójọ àwọn orílẹ̀-èdè bíi Gbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè (olórúkọ)|GIO oloruko lagbaye]] ati idamarun GIO agbaye fun [[purchasing power parity|ipin agbara iraja]]).<ref>The [[European Union]] has a larger collective economy, but is not a single nation.</ref>
Ìlà 116:
{{Countries of North America}}
 
[[Ẹ̀ka:Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà| ]]
[[Ẹ̀ka:Àwọn orílẹ̀-èdè Àríwá Amẹ́ríkà|Amerika]]
[[Ẹ̀ka:Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà| ]]