Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Yunifásítì Howard"

Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
}}
 
'''Yunifásítì Howard''' ('èdè Gẹ̀ẹ́sì: '''Howard University''' tàbí '''Howard''' tàbí '''HU''') ni yunifásítì [[private university|aládáni]], tó ní ìwé áṣẹ látọwọ́ ìjọba àpapọ̀ tó bùdó sí [[Washington, D.C.]] ní Amẹ́ríkà. Yunifásítì Howard jẹ́ ìkan nínú [[historically black colleges and universities|àwọn yunifásítì tí wọ́n dásílẹ̀ fún àwọn aláwọ̀dúdú]] (HBCU) ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Wọ́n dá Yunifásítì Howard sílẹ̀ ní 1867.