Ayé: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 55:
[[Fáìlì:The Earth seen from Apollo 17.jpg|thumbnail|Ile-aye]]
 
'''Ayé''', '''Ilé-ayé''' tabi '''AyéIlẹ̀-ayé ''' jẹ́ [[pálánẹ́tì]] kẹta bẹ́rẹ́ní ìbẹ́rẹ́ láti ọ̀dọ̀ [[Sun|oòrùn]], ó sìn jẹ́ èyí tí ó tóbi jùlo nínú àwọn pálánẹ̀tì tì wọ́n ní ilẹ́ tí ó ṣeè tẹ̀.
 
Ilé-ayé jé pálánẹ́tì àkọ́kọ́ tí ó ní omi tó ń sàn ní odeojú rè. bẹ́ẹ̀ sìni Ilé-ayé nìkan ni plánétì ti a mọ̀ ní [[àgbálá-aye]] (universe) tí o ní ohun ẹlẹ́mí. Ayé ní [[padà gbẹ́ringbẹ́rin]] tó jẹ́ pé lápapọ̀ mò [[ojú-òorun]] (atmosphere) tó jẹ́ kìkì nitrogen àti oxygen n dà àbò bo ilé-ayé lọ́wọ́ [[àtàngbóná]] (radiation) tó léwu si eni. Bakanna ojú-òorun ko gbà àwọn [[yanrín-oòrun]] lááyé láti jábò si ilé-ayé nípa sísùn wọn níná ki wọn o to le jábò sí ilé-ayé. <ref name=cazenave_ahrens1995>{{cite book | first=Anny | last=Cazenave | editor=Ahrens, Thomas J | year=1995 | title=Global earth physics a handbook of physical constants | publisher=American Geophysical Union | location=Washington, DC | isbn=0-87590-851-9 | url=http://www.agu.org/reference/gephys/5_cazenave.pdf | archiveurl=http://web.archive.org/web/20061016024803/http://www.agu.org/reference/gephys/5_cazenave.pdf | archivedate=2006-10-16 | accessdate=2008-08-03 | format=PDF | chapter=Geoid, Topography and Distribution of Landforms }}</ref>
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ayé"