Ijọidi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
New page: IJOID Ijoidi Apá gúúsù ilè Nigeria ni a ti rí àwon tí wón ń so èdè yìí. Èdè náà ni a mò sí Defaka àti Ijo. Jenewari àti Williamson (1989)...
 
No edit summary
Ìlà 1:
Apá gúúsù ilè Nigeria ni a ti rí àwon tí wón ń so èdè yìí. Èdè náà ni a mò sí Defaka àti Ijo. Jenewari àti Williamson (1989) ni wón se àgbékalè àte isálè yìí
[[IJOID]]
 
[[Ijoidi]]
 
Apá gúúsù ilè Nigeria ni a ti rí àwon tí wón ń so èdè yìí. Èdè náà ni a mò sí Defaka àti Ijo. Jenewari àti Williamson (1989) ni wón se àgbékalè àte isálè yìí
Nínú àte yìí, a rí ‘Proto-Ijoid’ tí ó pín sí Defaka ati Ijo. Ijo pín Ìlà-oòrùn àti ìwò oòrùn.
Lábé ìlà-oòrùn ni a ti rí: Nkoro, Ibani, Kalabari, Kirike (Okrika), Nembe ati Akaha(Akassa).
Lábé ìwò-oòrùn ni a ti rí : Izon, Biseni, Akita (Okordia), Oruma
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ijọidi"