Èdè Wolof: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
+vidéo Wikitongues
 
Ìlà 17:
|lc1=wol|ld1=Wolof|ll1=none
|lc2=wof|ld2=Gambian Wolof}}
[[File:WIKITONGUES- Aminah Abba speaking Wolof.webm|thumb|left|Èdè Wolof]]
'''Ede Wolof''' jẹ èdè tí à ń sọ ni atí bèbè [[Senegal]] Mílíọ̀nù méjì-àbọ̀ niye àwọn tó ń sọ. Awọn Olùbágbè wọn ni Mandika ati Fulaní. Awọn isẹ́ ọna wọn màa ń rewà tó sì ma ń ní àmìn àti àwòràn àwọn asáájú nínú ẹ̀sìn musulumi. Ìtan [[Wolof]] ti wà láti bí ẹgbẹ̀rún ọdún méjìlá tàbí métàlá sẹ́yìn. Ìtàn ẹbí alátẹnudẹ́nu wọn sọ pé ọ̀kan lára àwọn tó kọkọ tẹ̀dó síbí yìí jẹ́ awọn to wa láti orífun Fulbe. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìtàn Wolof ni a le rí nínú àwọn orin oríkì èyí ti a ma ń gbọ́ láti ẹnu àwọn ‘Griots’ àwọn akéwì. Mùsùlùmí ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọnm ará Wolof.