King's College: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
#WPWP
Ìmúkúrò àtúnyẹ̀wò 535862 ti T Cells (ọ̀rọ̀) #WPWPMK
Ìlà 38:
 
== Ìtàn nípa rẹ̀ ==
 
[[File:Kings College, Lagos1.jpg|Kings College, Lagos1]]
Ní ọdún  1908, alákóso ètò ẹ̀kọ́ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, [[Henry Rawlingson Carr]]
gba Gómìnà Walter Egerton ní ìyànjú lórí ètò ẹ̀kọ́ ní Ìpínlẹ̀ Èkó.<ref name="Fajana">{{Cite web|last1=Fajana|first1=Adewumi|title=Henry Carr - Portrait of a Public Servant|url=http://www.unilorin.edu.ng/journals/education/ije/june1984/HENRY%20CARR%20-%20PORTRAIT%20OF%20A%20PUBLIC%20SERVANT.pdf|accessdate=4 October 2015|access-date=4 October 2015}}</ref> Ìyànjú Carr àti àwọn ìmòràn rẹ̀ ní ó jẹ́ kí wọ́n dá King's College sílẹ̀. Carr jẹ́ kí àwọn London Board of Education ri wípé dídá ilé ìwé yìí sílẹ̀ maa mú ìtẹ̀síwájú bá ètò wọ́n nípa ẹ̀kọ́ ní àwùjọ.<ref name="Fajana">{{Cite web|last1=Fajana|first1=Adewumi|title=Henry Carr - Portrait of a Public Servant|url=http://www.unilorin.edu.ng/journals/education/ije/june1984/HENRY%20CARR%20-%20PORTRAIT%20OF%20A%20PUBLIC%20SERVANT.pdf|accessdate=4 October 2015|access-date=4 October 2015}}</ref> Fún ìdí èyí, àwọn olùkọ̀wé kan maa ń pe Henry Carr ní "atukọ̀ King's College".<ref name="Adeniran">{{Cite book|last1=Adeniran|first1=Adedapo|title=he Case for Peaceful and Friendly Dissolution of the Artificial Entity Christened Nigeria by the British Colonial Imperialists|publisher=Adedapo Adeniran Esquire of Lincoln's Inn, 2002|isbn=9789783485877|ISBN=9789783485877|page=44|url=https://books.google.com/books?id=5hDJvxt_O-MC&pg=PT24&lpg=PT24&dq=henry+carr+case+peaceful+dissolution&source=bl&ots=vwmK4S3Ltu&sig=-I-CtkdKJcQVppwsnnC6PqfqpqY&hl=en&sa=X&ved=0CB4Q6AEwAGoVChMI94T3p_qnyAIVhDw-Ch2FhgQs#v=onepage&q=henry%20carr%20case%20peaceful%20dissolution&f=false|access-date=4 October 2015|accessdate=4 October 2015}}</ref><ref name="Naij">{{Cite web|last1=Olupohunda & Olalere|title=How Lagos Was Responsible For Nigeria's {{sic|nolink=y|Indepedence}}|url=https://www.naij.com/577472-nigeriaat55-read-lagos-won-nigerias-independence-britain.html|accessdate=4 October 2015|access-date=4 October 2015}}</ref>