Egungun: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

46 bytes added ,  22 Oṣù Kẹfà 2020
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
No edit summary
No edit summary
|Caption2 = A [[scanning electron microscope|scanning electronic micrograph]] of bone at 10,000× magnification.
}}
'''Egungun''' tàbí '''egun''' tàbí '''eegun''' ni [[organ (anatomy)|ìfun inú ara]] [[Stiffness|líle]] tó ṣe àpapọ̀ gbogbo [[skeleton|egungun-ara]] àwọn ẹranko [[vertebrate|elégungun]]. Àwọn egun únṣe àbò fún orísi àwọn ìfun inú ara, wọ́n únṣẹ̀dá àwọn [[red blood cell|ìhámọ́ ẹ̀jẹ̀ pupa]] àti [[white blood cell|ìhámọ́ ẹ̀jẹ̀ funfun]] tí wọ́n jẹ́ àkóónú [[ẹ̀jẹ̀]], wọ́n únṣe ìkópamọ́ àwọn [[mineral|ohun amọ́ralókun]], wọ́n únṣe ọ̀nà-ìkọ́ àti ìmúdúró fún ara, wọ́n sì úngba [[animal locomotion|ìmúrìn]] ní àyè. Àwọn egun wà bíi orísirísi.