Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Egungun"

28 bytes removed ,  18:16, 22 Oṣù Kẹfà 2020
#WPWPZM
(section heading; Reflist template; stub template)
(#WPWPZM)
 
'''Egungun''' tàbí '''egun''' tàbí '''eegun''' ni [[organ (anatomy)|ìfun inú ara]] [[Stiffness|líle]] tó ṣe àpapọ̀ gbogbo [[skeleton|egungun-ara]] àwọn ẹranko [[vertebrate|elégungun]]. Àwọn egun únṣe àbò fún orísi àwọn ìfun inú ara, wọ́n únṣẹ̀dá àwọn [[red blood cell|ìhámọ́ ẹ̀jẹ̀ pupa]] àti [[white blood cell|ìhámọ́ ẹ̀jẹ̀ funfun]] tí wọ́n jẹ́ àkóónú [[ẹ̀jẹ̀]], wọ́n únṣe ìkópamọ́ àwọn [[mineral|ohun amọ́ralókun]], wọ́n únṣe ọ̀nà-ìkọ́ àti ìmúdúró fún ara, wọ́n sì úngba [[animal locomotion|ìmúrìn]] ní àyè.<ref name="Publishing">{{cite web | last=PublBishing | first=Argosy | title=Types of Bones - Learn Skeleton Anatomy | website=Visible Body | url=https://www.visiblebody.com/learn/skeleton/types-of-bones | access-date=2019-06-06}}</ref> <ref name="KidsHealth">{{cite web | title=Bones, Muscles, and Joints (for Parents) | website=KidsHealth | url=https://kidshealth.org/en/parents/bones-muscles-joints.html?WT.ac=ctg | access-date=2019-06-06}}</ref>
Àwọn egun wà bíi orísirísi.
 
 
{{Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}
 
==Àwọn Ìtọ́kasí ==