Tẹlifóònù: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 5:
 
Ẹ̀rọ tẹlifóònù ní [[microphone|gbohùngbohùn]] kan (''ẹ̀rọ ìfiránṣẹ́''', ''transmitter'') láti fi sọ̀rọ̀ àti [[earphone|ẹ̀rọ ìgbọ́ràn]] (''ẹ̀rọ olùgbà'', ''receiver'') láti fi gbé ohùn jáde.<ref>{{Cite web|url=https://media.defense.gov/2017/Mar/16/2001717399/-1/-1/0/CIM_9430_1.PDF|title=United States Coast Guard ''Sound-Powered Telephone Talkers Manual'', 1979, p. 1}}</ref> Bákannáà, tẹlifóònù tún ní ''ago'' tó ún polongo ìpè tẹlifóònù tó únbọ̀, ó tún ní ẹ̀rọ ayíwọ́ tàbí bọ́tìnì láti fi tẹ [[telephone number|nọ́mbà tẹlifóònù]] fún ìpè tẹlifóònù míràn. Ẹ̀rọ ìgbọ́ràn àti ẹ̀rọ ìfiránṣẹ́ wà papọ̀ nínú tẹlifóònù kannáà tí a gbé sí etí àti ẹnu nígbà tí a bá ún sọ̀rọ̀. Ẹ̀rọ ìfiránṣẹ́ ún yí [[sound wave|ohùn]] sí [[Signal (information theory)|àmi ẹ̀rọ-oníná]] tó únjẹ́ fífi ránṣẹ́ látorí ìsopọ̀mọ́ra tẹlifóònù sí tẹlifóònù tó úngba ìpè, níbi tó ti únyí àmì náà sí ohùn tó ṣe é gbọ́ létí pẹ̀lu ẹ̀rọ ìgbọ́ràn tàbí nígbà míràn pẹ̀lú [[loudspeaker|ẹ̀rọ asọ̀rọ̀pariwo]]. Àwọn tẹlifóònù jẹ́ àwọn ẹ̀rọ [[duplex (telecommunications)|duplex]], tó túmọ́si pé wọ́n ún gba ìgbéránṣẹ́ lọ àti bọ̀ ní ẹ̀kannáà.
 
==Àwọn ìtọ́kasí==
 
[[ẹ̀ka:Ìṣiṣẹ́ fóònù]]