Ìbánisọ̀rọ̀: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
 
Ìlà 8:
# Kókó tí a fẹ́ fi múlẹ̀ inú iṣẹ́ tí a rán jáde.
# Bí a ṣe ránṣẹ́ náà jáde tàbí ọ̀nà tí a gbà gbé iṣẹ́ náà léde.
# Ariwo. Èyí ma ń mú ìdíwọ́ wá nínú ìgbésẹ̀ ìbára-ẹni sọ̀rọ̀, tí kìí sì jẹ́ kí á gbọ́ ara ẹni é bí a bá ń sọ̀rọ̀ lọ. Ariwo yí lè jẹ́ ìmọ̀ọ́mọ̀ ṣe tàbí àìmọ̀ọ́mọ̀ ṣe.<ref name="Toppr-guides 2018">{{cite web | title=Communications: Process, Importance, Types, Barriers with Examples | website=Toppr-guides | date=2018-06-11 | url=https://www.toppr.com/guides/business-studies/directing/communication/ | access-date=2020-06-26}}</ref>
#Àgbékalẹ̀ iṣẹ́ tí a fẹ́ rán sí olùgbọ́ wa tí yóò fi gbọ́nwa yé yéké-yéké
# Àgbọ́yé iṣẹ́ tí olùfiránṣẹ́ fi ránṣẹ́ síwa lásìkò ìbánisọ̀rọ̀.