Wikipẹ́díà l'édè Yorùbá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
 
Ìlà 13:
| author =
}}
'''Wikipẹ́díà l'édè Yorùbá''' ni àgbéjáde [[Wikipedia]] ní [[èdè Yorùbá]]. Ó bẹ̀rẹ̀ ní osù kẹwàá ọdún 2002,<ref name="Stats">[http://stats.wikimedia.org/EN/TablesWikipediaYO.htm Wikipedia Statistics Yoruba]</ref> lọ́wọ́lọ́wọ́ ó ní iye àyọkà {{NUMBEROF|ARTICLES|yo}} àti àwọn oníṣe aforúkọsílẹ̀ {{formatnum:{{#expr:{{NUMBEROF|USERS|yo}}}}}}, Wikipẹ́díà l'édè Yorùbá ní Wikipedia ẹ̀kẹta tótóbijùlọ nínú àwọn èdèWikipẹ́díà l'édè Áfríkà lẹ̀yìn èdè [[Arabic language|Lárúwábá]] àti [[Swahili language|èdè Swahili]], òhun ni Wikipedia 105k tótóbijùlọ nínú àwọn èdè lágbàáyé. Wikipẹ́díà l'édè Yorùbá ti jẹ́ ìkan nínú àwọn Wikipedia aléwájúaṣíwájú 3 tàbí 4 Wikipedia l'édè Áfríkà bóṣejẹ mọ́ iye àwọn àyọkà tó ní láti ọdún 2008.<ref name="Meta">[https://meta.wikimedia.org/wiki/African_languages "African languages," Wikimedia Meta-Wiki]</ref>
 
Ní ọdún 2012 ní ibi ìpàdé Wikimania 2012, [[Jimmy Wales]] fún ìkan nínú àwọn olóòtú Wikipẹ́díà l'édè Yorùbá ní ẹ̀yẹ ẹ̀bùn [[Wikipedian of the Year]] fún ìkópa àti iṣẹ́ rẹ̀ lórí Wikipẹ́díà l'édè Yorùbá.<ref name="Stats" /><ref name="Meta" /><ref>[https://en.wikinews.org/wiki/Wikimania_2012_tackles_diversity_issues "Wikimania 2012 tackles diversity issues," ''Wikinews'', 14 July 2012]</ref>