Àwọn ẹ̀yà Xhosa: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Ṣ'èdá ojúewé pẹ̀lú "{{Infobox ethnic group | group = Xhosa <br /> AmaXhosa | image = | caption = | population = 8,104,752 (2011 Census) | regions..."
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 19:04, 12 Oṣù Keje 2020

Àdàkọ:Infobox Bantu name

Xhosa
AmaXhosa
Àpapọ̀ iye oníbùgbé
8,104,752 (2011 Census)
Regions with significant populations
 Gúúsù Áfríkà 7,834,203

Eastern Cape: 5,092,152
Western Cape: 1,403,233
Gauteng: 796,841
Free State: 201,145
KwaZulu-Natal: 340,832

 Zimbabwe 200,000[1]
Èdè

Xhosa

Ẹ̀sìn

traditional African religions, Christianity

Ẹ̀yà abínibí bíbátan

Zulu, Hlubi, Swati and Southern and Northern Ndebele people

Àwọn ẹ̀yà Xhosa' ( /ˈkɔːsə,_ˈksə/;[2][3] Àdàkọ:IPA-xh) (pípè ní Yorùbá bíi Kósà) ni ẹ̀ka ẹ̀ya àwọn Bantu tó búdò sí Apágúúsù Áfríkà àgàgà ní Eastern Cape. Àwọn ẹ̀yà Xhosa kékeré (Mfengu) tún wà ní Zimbabwe, níbi tí èdè wọn, isiXhosa, ti jẹ́ gbígbà bíi èdè ọmọ orílẹ̀-èdè.[4]


Itokasi

  1. Hlenze Welsh Kunju, 2017 Isixhosa Ulwimi Lwabantu Abangesosininzi eZimbabwe: Ukuphila Nokulondolozwa Kwaso, PhD Dissertation, Rhodes University.
  2. "Xhosa – pronunciation of Xhosa". Macmillan Dictionary. Macmillan Publishers Limited. Retrieved 16 April 2014. 
  3. Laurie Bauer, 2007, The Linguistics Student's Handbook, Edinburgh
  4. Nombembe, Caciswa. "Music-making of the Xhosa diasporic community: a focus on the Umguyo tradition in Zimbabwe." Masters dissertation, School of Arts, Faculty of Humanities, University of the Witwatersrand, 2013.