Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 15 ọdún 2020: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k Dáàbò bòó "Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 15 ọdún 2020" ([Àtúnṣe=Gba àwọn alámùójútó nìkan láyè] (kòdájú) [Ìyípò=Gba àwọn alámùójútó nìkan láyè] (kòdájú))
No edit summary
 
Ìlà 6:
Naijiria ni orile-ede to ni onibugbe pupojulo ni Afrika, [[list of countries by population|ikejo ni agbaye]], be si ni o je orile-ede to ni awon [[Black people|eniyan alawodudu]] julo laye. O je kikojo mo ara awon orile-ede ti a n pe "Next Eleven" ni to ri okowo won, o si tun je ikan ninu Ajoni awon Ibinibi. Okowo ile naijiria je ikan ninu eyi to n dagba kiakiajulo laye, pelu [[IMF]] to ngbero idagba 9% fun 2008 ati 8.3% fun 2009. Ni ibere awon odun 2000, ogunlogo awon onibugbe gbe pelu iye to din ju US$ 1.25 (PPP) lojumo. Naijiria ni okowo re tobijulo ni Afirika, ati alagbara ni agbegbe [[Iwoorun Afirika]]. '([[Nàìjíríà|ìyókù...]])'
 
<noinclude>[[Ẹ̀ka:Àwọn àyọkà ọ̀ṣẹ̀|2020]]</noinclude>