Àjàkáyé-àrùn: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 1:
'''Àjàkálẹ̀-àrùn tókárí-ayé''' (láti inú èdè Greek túnmọ̀ sí pan, "gbogbo àti demo, "ènìyàn") jẹ ìbújáde àkóràn àrùn kan ti o nlọ kaa kiri [[orílẹ̀-èdè]] tàbí ẹkùn tí ó ju ẹyọkan lọ. Yíyára tànkálẹ̀ àrùn laarin ọ̀pọ̀ [[ènìyàn]] ní agbegbè tàbí ẹkùn fún ìwọ̀nba ìgbà diẹ ni wọ́n npe ni "[[àjàkálẹ̀-àrùn]]" (epidemic).<ref name="CDC 2017">{{cite web|title=Principles of Epidemiology: Home - Self-Study Course SS1978|website=CDC|date=2017-04-26|url=https://www.cdc.gov/csels/dsepd/ss1978/index.html|access-date=2020-07-13}}</ref> Ìtànkálẹ̀ àrùn tí ó jẹ́ wípé o ní iye ìwọ̀nba àwọn ènìyàn tí wọ́n ko o ni wọ́n ń pè ní "endemic" ki i se àjàkálẹ̀-àrùn tókárí-ayé. Àrùn endemic tí ó jẹ́ wípé o ní iye àwọn ènìyàn tí wọ́n ko o tí kì í ṣe wípé ó tàn kaa kiri bi àjàkálẹ̀-àrùn ti o ma n ṣẹyọ ní àkókò ni a le yà sọ́tọ̀ nítorí pé àwọn àrùn bayi i ma n wáyé leekanna ni àwọn ẹkùn tí ó tóbi ní àgbáyé sùgbọ́n wọ́n ki i ràn kaa kiri àgbáyé.
=Àpilẹ̀kọ lórí àjàkálẹ̀-àrùn tókárí-ayé=
Àjàkálẹ̀-àrùn tókárí-ayé (láti inú èdè Greek túnmọ̀ sí pan, "gbogbo àti demo, "ènìyàn") jẹ ìbújáde àkóràn àrùn kan ti o nlọ kaa kiri [[orílẹ̀-èdè]] tàbí ẹkùn tí ó ju ẹyọkan lọ. Yíyára tànkálẹ̀ àrùn laarin ọ̀pọ̀ [[ènìyàn]] ní agbegbè tàbí ẹkùn fún ìwọ̀nba ìgbà diẹ ni wọ́n npe ni "[[àjàkálẹ̀-àrùn]]" (epidemic).<ref name="CDC 2017">{{cite web|title=Principles of Epidemiology: Home - Self-Study Course SS1978|website=CDC|date=2017-04-26|url=https://www.cdc.gov/csels/dsepd/ss1978/index.html|access-date=2020-07-13}}</ref> Ìtànkálẹ̀ àrùn tí ó jẹ́ wípé o ní iye ìwọ̀nba àwọn ènìyàn tí wọ́n ko o ni wọ́n ń pè ní "endemic" ki i se àjàkálẹ̀-àrùn tókárí-ayé. Àrùn endemic tí ó jẹ́ wípé o ní iye àwọn ènìyàn tí wọ́n ko o tí kì í ṣe wípé ó tàn kaa kiri bi àjàkálẹ̀-àrùn ti o ma n ṣẹyọ ní àkókò ni a le yà sọ́tọ̀ nítorí pé àwọn àrùn bayi i ma n wáyé leekanna ni àwọn ẹkùn tí ó tóbi ní àgbáyé sùgbọ́n wọ́n ki i ràn kaa kiri àgbáyé.
 
=Itunmo ati Ipele=
Line 52 ⟶ 51:
===Kokoro zika===
Ibiujade kokoro zika bere ni odun 2005 ti o si n tesiwaju kikankikan ni gbogbo ibere odun 2016 pelu awon isele ti o ju 1.5 million lo jake jado awon orile-ede ti o ju mejila lo ni ilu America. Ajo ti o n ri si eto ilera ni agbaye, World Health Organization se ikilo pe arun zika ni agbara lati di ajakale-arun ti yio tan ka gbogbo agbaalaaye ti won ko ba tete dena re.
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
==Itokasi==
{{reflist}}
[[Ẹ̀ka:Ìmọ̀ àjákálẹ̀-àrùn]]