Ọ̀jọ̀gbọ́n Ṣiyan Oyèwẹ̀sọ̀: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 1:
''' Ṣiyan Oyeweso''' tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kíní oṣù Kejì, ọdún 1961. <ref name="Nigerian Voice">{{cite web | title=50 GOLDEN CHEERS TO SIYAN OYEWESO | website=Nigerian Voice | url=https://www.thenigerianvoice.com/news/46459/50-golden-cheers-to-siyan-oyeweso.html | access-date=2019-12-29}}</ref> Ìta Ìdí-Ọmọ ní agbègbè Ọjà Ọba ní ìlú [[Ìbàdàn]] ní ìpínlẹ̀ [[Ọ̀yọ́]], sínú ẹbí ẹlẹ́sì [[Islam]]. Ìdílé Oyeweso ni wọ́n ṣẹ̀ wá láti agbolé Olójò ní ìlú [[Ẹdẹ]] ní [[ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun]] ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]]. <ref name=" benfestus@federalpolyede.edu.ng">{{cite web | author= benfestus@federalpolyede.edu.ng | title=Federal Polytechnic Ede, Osun State, Nigeria | website=Federal Polytechnic Ede, Osun State, Nigeria | url=https://www.federalpolyede.edu.ng/council/?fpe=8 | access-date=2019-12-29}}</ref>
==Ìrínké-rindò Ẹ̀kọ́ rẹ̀==
Ó jáde láti Ilé ẹ̀kọ́ Míràn pẹ̀lú àmì tó peregedé jùlọ ní ọdún 1987. Ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìtàn láti ọdún 1978 sí 1982, ní Ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì [[Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀]] tí ó sì jáde pẹ̀lú ìpele gíga jùlọ ẹlẹ́kejì (Second Class Upper). Ó sì kẹ́kọ̀ọ́ gboyè M.A àti Ph.D tí ó sọọ́ di Ọ̀mọ̀wé nínú ìmọ Intellectual History ní Ilé-ẹ̀kọ́ kan náà. <ref name="P.M. News 2019">{{cite web | title=Mobolaji Johnson Colloquium: Leaders advised to render impactful governance | website=P.M. News | date=2019-11-28 | url=https://www.pmnewsnigeria.com/2019/11/28/mobolaji-johnson-colloquium-leaders-advised-to-render-impactful-governance/ | access-date=2019-12-29}}</ref>