Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 ní Eritrea"

(wikilink in lead sentence)
 
== Àwọn ìgbésẹ̀ láti dènà àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 ==
Láti dènà àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19, ìjọba ti rọ àwọn ará ìlú làti má ṣe rin ìrìn-àjò lọ kúrò tàbí wá sí orílẹ̀-èdè Eritrea. Àwọn arìnrìn àjò tí wọ́n ń bọ̀ wá sí orílẹ̀-èdè Eritrea, ṣùgbọ́n tí wọ́n ti ṣe àbẹ̀wò sí orílẹ̀-èdè China, [[Italy]], [[SouthKòréà koreaGúúsù]] tàbí [[Iran]] láìpẹ́ yi ni ìjọba ti kọ lọ sí ibi ìfinipamọ́ láti ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹta ọdún 2020.<ref name="AfricaNews 20203">{{cite web|author=AfricaNews|title=Eritrea coronavirus: Expats repatriated, caseload at 251|website=Africanews|date=2020-07-19|url=https://www.africanews.com/2020/07/19/eritrea-s-coronavirus-rules-chinese-italians-iranians-to-be-quarantined/|access-date=2020-08-01}}</ref>
 
Lára àwọn ìlànà tí ìjọba gbé kalẹ̀ ni láti dènà gbígbé owó lórí àwọn ọjà làkòókò ìsémọ́lé. Àwọn àmúṣe ìgbésẹ̀ yí ni wọ́n ti kéde wọn ní àwọn agbègbè bi i [[Massawa]].<ref name="Mafotsing 20202">{{cite web|last=Mafotsing|first=Line|title=Covid-19 and Eritrea’s Response|website=Kujenga Amani|date=2020-05-14|url=https://kujenga-amani.ssrc.org/2020/05/14/covid-19-and-eritreas-response/|access-date=2020-08-01}}</ref>