Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Kaycee Madu"

78 bytes added ,  15:36, 27 Oṣù Kẹjọ 2020
Ẹ̀ka; DEFAULTSORT; intro paragraph wikilink with EN:YO
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
(Ẹ̀ka; DEFAULTSORT; intro paragraph wikilink with EN:YO)
| alma_mater=
}}
'''Kaycee (Kelechi) Madu''' jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà <ref name="TheCable 2020">{{cite web | title=CLOSE-UP: Madu, Nigerian-born lawyer, appointed justice minister in Canadian province | website=TheCable | date=2020-08-26 | url=https://www.thecable.ng/close-up-madu-nigerian-born-lawyer-appointed-justice-minister-in-canadian-province | access-date=2020-08-27}}</ref><ref name="The Sun Nigeria 2020">{{cite web | title=Obi hails Kaycee Madu on new appointment | website=The Sun Nigeria | date=2020-08-27 | url=https://www.sunnewsonline.com/obi-hails-kaycee-madu-on-new-appointment/ | access-date=2020-08-27}}</ref> ṣùgbọ́n tí ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí amọ̀fin àti òṣèlú ní orílẹ̀ èdè Canada[[Kánádà]]. Òun ni Mínísítà aṣẹ̀ṣẹ̀yàn Ìpínlẹ̀ Alberta ní orílẹ̀-èdè CanadaKánádà. Wọ́n dìbò yàn-án sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin tí Ìpínlẹ̀ Alberta lọ́dún 2019, láti ṣojú ẹkùn ìdìbò [[electoral district]].<ref>{{cite web|author=Derek Van Diest Updated: April 16, 2019 |url=https://edmontonjournal.com/news/politics/results-kacyee-madu-wins-edmonton-south-west-in-tightly-contested-battleground |title=Results: Kacyee Madu wins Edmonton-South West in tightly contested battleground |publisher=Edmonton Journal |date= |accessdate=2019-04-17}}</ref> Lọ́gbọ̀n ọjọ́ oṣù kẹrin ọdún 2019,Wọ́n Madu sínú Ìgbìmọ̀ ìṣèjọba, [[Executive Council of Alberta]] gẹ́gẹ́ bí Mínísítà fún ètò olú-ìlú náà. Ìpò yìí ló dìmú títí dọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 2020 tí wọ́n tún fi yàn án gẹ́gẹ́ bí Mínísítà ètò ìdájọ́ àti Amọ̀fin-àgbà ní Alberta lórílẹ̀-èdè CanadaKánádà.
 
Pẹ̀lú àṣẹ láti òfin ìgbìmọ̀ iìṣèjọba, Gómìnà Ìpínlẹ̀ Alberta fún Madu ni oyè Queen's Counsel lọ́jọ́ kẹrin oṣù kẹta ọdún 2020. Oyè Queen's Counsel ni oyè tí ó ga jùlọ tí wọ́n máa ń fún àwọn aṣòfin tó bá dáńgájíá nípa ìdàgbàsókè òfin àti ìlú
==Àwọn Ìtọ́kasí==
{{Reflist}}
 
{{DEFAULTSORT:Madu, Kaycee}}
[[Ẹ̀ka:Àwọn ará Kánádà]]