Pápá Parsonage ní Nuenen: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
Ìlà 34:
 
Àwọn àwòrán wọ̀nyí wà nínú àkójọpọ̀ àwọn ohun méèlegbàgbé ní ilé ìtọ́jú àwọn ohun méèlegbàgbé ní [[Netherlands]] lọ́dún 1962 sí 2020. Lọ́gbọ̀n ọjọ́ oṣù kẹta ọdún 2020, wọ́n jí àwọn nǹkan wọ̀nyí kó níbi ìpàtẹ kan ní ilé ìtọ́jú ohun méèlegbàgbé ní [[Laren, North Holland|Laren]], lẹ́yìn tí wọ́n tì í pa nítorí [[àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19]]. <ref name="artnet News 2020" />
 
==Ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀==
Arákùnrin Van Gogh gbé ní [[The Hague]] pẹ̀lú [[Sien Hoornik]] lẹ́yìn èyí ó dá gbé fún oṣù díẹ̀ ní [[Drenthe]] lápá àríwá orílẹ̀-èdè [[Netherlands]]. Lẹ́yìn èyí, ó lọ gbé ní ilé ìgbé àwọn àlùfáà tí [[Dutch Reformed Church]] ní [[Nuenen]] lẹ́bàá [[Eindhoven]] lóṣù Kejìlá ọdún 1883 níbi tí bàbá rẹ̀ ti ń ṣiṣẹ́ àlùfáà.<ref name="Route">{{cite web |title=Vincent van Gogh in Nuenen, The Netherlands | website=Van Gogh Route | url=https://www.vangoghroute.com/the-netherlands/nuenen/ | access-date=30 March 2020}}</ref> Ẹbí rẹ̀ yí ilé ìfọṣọ tí ó wà ní ẹ̀yìnkùlé wọ́n sí ilé ayawòrán .<ref>{{cite web |url=http://www.vangoghmuseum.nl/vgm/index.jsp?page=1564&collection=619&lang=en |title=The Vicarage at Nuenen, 1885 |year=2005–2011 |work=Permanent Collection |publisher=Van Gogh Museum |archive-url=https://web.archive.org/web/20071028073701/http://www.vangoghmuseum.nl/vgm/index.jsp?page=1564&collection=619&lang=en |accessdate=15 May 2011|archive-date=28 October 2007 }}</ref>
 
Van Gogh wà pẹ̀lú àwọn òbí rẹ̀ ní Nuenen fún nǹkan bí ọdún méjì, ní àkókò yìí ó ya oríṣiríṣi àwòrán tó tọ́ igba, lára èyí tí iṣẹ́ àkọ́kọ́ tó gbajúmọ̀ tí wọ́n ń pè ní ''[[The Potato Eaters]]''. Ó kó lọ sí ìlú [[Antwerp]] lóṣù kọkànlá ọdún 1885<ref name="Van Gogh Museum">{{cite web | title=Peasant Painter | website=Van Gogh Museum | url=https://www.vangoghmuseum.nl/en/vincent-van-gogh-life-and-work/van-goghs-life-1853-1890/peasant-painter | access-date=31 March 2020}}</ref> lẹ́yìn náà, ó tún kó lọ sí Paris lọ́dún 1886.<ref name="The New York Times 2013">{{cite news|last=Siegal|first=Nina|url=https://www.nytimes.com/2013/10/17/arts/international/becoming-vincent-van-gogh-the-paris-years.html|title=Becoming Vincent Van Gogh: The Paris Years|date=October 16, 2013|work=[[The New York Times]]|publisher=[[New York Times Company]]|location=New York City|access-date=March 31, 2020|url-status=live|archive-url=https://web.archive.org/web/20131116032131/https://www.nytimes.com/2013/10/17/arts/international/becoming-vincent-van-gogh-the-paris-years.html|archive-date=November 16, 2013|url-access=limited}}</ref>
 
==Àwọn Ìtọ́kasí==