Genevieve Nnaji: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
Ìlà 13:
 
==Iṣẹ́ ọwọ́==
Nnaji bẹ̀rẹ̀ ìṣèré rẹ̀ láti ọmọdé ninu eré tẹlifísọ̀n ''Ripples'' nígbà tójẹ́ ọmọ ọdún 8méjọ. Ó tún ṣe ìpolówó ọjà bíi méèló kan nínú èyí tó jẹ́ fún Pronto àti ọṣẹ ìfọsọ Omo. Ní 2004 ó di aṣojú fún ọsẹ ìwẹ̀ Lux<ref>[http://www.unileverghana.com/ourbrands/personalcare/lux.asp Genevieve Nnaji & Lux advertisement]</ref>, ìbáṣe ìgbọ̀wọ́ tọ́ fa èrè ínlá wá fun.<ref name=info1/>
 
Ni 1998 nígbà tójẹ́ ọmọ ọdún 19 wọn ṣe àmúhàn rẹ̀ sí àwọn olólùfẹ́ sinima-agbelewo ni Nàìjíríà pẹ̀lú filmu tó ún jẹ́ ''Most Wanted''. Lẹ́yìn rẹ̀ ó tún ṣe àwọn sinima-agbelewo bíi ''Last Party, Mark of the Beast'' àti ''Ijele''. Ó ti kópa nínúu filmu tó tó 80 ni Nollywood.<ref>[http://hollywood.premiere.com/movie_stars/celebrity-filmography-Genevieve+Nnaji Àkójọ àwọn filmu Genevieve Nnaji]</ref>