Ìran Yorùbá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 19:
|langs=[[Èdè Yorùbá|Yorùbá]], [[Àwọn èdè irú Yorùbá|Ìran èdè Yorùbá]]
|rels=[[Ẹ̀sìn Krístì]] 40%, [[Ìmàle]] 50%, Ijuba [[Òrìṣà]] ati [[Ifá|Ẹ̀sìn Ifá]] 10%.
|related-c= [[ỌmọÌran Ẹdó]], [[Tapa]], [[Igala]], [[Itsekiri]], [[Ìgbìrà]]
}}
'''Àwọn ọmọ Yorùbá ''' ti a pè ni ẹ̀nìyàn Yorùbá ni ibí yìí pọ̀ gan-an ni. Ilẹ̀ Yorùbá ni púpò nínú wọ́n wa ni [[ìpínlẹ̀ Ẹdó]], [[Ìpínlẹ̀ Èkìtì]], [[Èkó]], [[Ìpínlẹ̀ Kwara]], [[ìpínlẹ̀ Kogí]], [[ìpínlẹ̀ Ògùn]], [[Ìpínlẹ̀ Òndó|Ìpínlẹ̀ Oǹdó]], [[ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun]], [[ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́|Ọ̀yọ́]]; àti wípé ọmọ Yorùbá wa ní orílẹ̀-èdè Olómìnira Benin ([[Benin|Dahomey]]), Sàró ([[Sierra Leone]]) àti [[Togo]], [[Brazil]], [[Cuba]], [[Haiti]], [[United States of America|Amẹ́ríkà]] ati Venezuela. Àwọn Yorùbá ni wọ́n se ipò keta ni pípò ni ilè [[Nàìjíríà]].