Ìran Yorùbá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 21:
|related-c= [[Ìran Ẹdó]], [[Tapa]], [[Igala]], [[Itsekiri]], [[Ìgbìrà]]
}}
'''Ìran Yorùbá''' tabi '''Àwọn ọmọ Yorùbá''' jé árá ìpinẹ̀yà osiìpinle ọ́wọ́ òsi ní orílẹ̀ Áfríkà. Wọn jé árá ìpin awọ́n ìran to pò ju ní orílẹ̀ Áfríkà. [[Ilẹ̀ Yorùbá]] ní púpò nínú wọ́n. Ẹ lè ri wọ́n ní ìpínlẹ̀ púpò bíi [[ìpínlẹ̀ Ẹdó]], [[Ìpínlẹ̀ Èkìtì]], [[Èkó|ìpínlẹ̀ Èkó]], [[Ìpínlẹ̀ Kwara]], [[ìpínlẹ̀ Kogí]], [[ìpínlẹ̀ Ògùn]], [[Ìpínlẹ̀ Òndó|Ìpínlẹ̀ Oǹdó]], [[ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun]], [[ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́]], àti ìpínlẹ̀ to wa nínú orílẹ̀-èdè Olómìnira Benin ([[Benin|Dahomey]]),. Ẹ tún le rí wọ́n ní orílẹ̀-èdè Sàró ([[Sierra Leone]]), àti awọ́n ìpínlẹ̀orílẹ̀ miiran bíi awón tí wọ́n pè ní [[Togo]], [[Brazil]], [[Cuba]], [[Haiti]], [[United States of America|Amẹ́ríkà]] ati Venezuela naa. Àwọn Yorùbá wà lárál'árá wọ́nawọ́n to tóbí ju ní [[Nàìjíríà|ilè Nàìjíríà]]. Ó le jẹ́ pe awọ́n lo tóbí ju, abí awón lo jẹ́ ikejì, abi awọ́n lo jẹ́ ikẹ́tá.
 
Àwọn Yorùbá jẹ́ àwọn ènìyàn kan ti èdè wón pín sí orísirísi. Àwọn Ìpín yíì ní a n ri; a máà lo ìpín èdè láti fi pé à èdè wa tí n se bi ti "Améríkà"; "Èkìtì"; "èkó"; "Ìjèbú"; "Ìjẹ̀ṣhà"; "Ìkálẹ̀"; "Ọ̀yó"; àti bebe lo. Láàrin èyí, la síì tún ní èdè ìfò tí nse àpẹẹrẹ èdè tó nípin si àwọn ìpín èdè tí o pọ̀.